Ifitonileti pe Ileeṣẹ Nestle Nigeria Plc n fẹẹ gba iwe ẹri aṣeyege lọwọ Ajọ to n ri si lilo omi lọna to dara ju lọ lagbaaye (Alliance for Water Stewardship (AWS).
Ileeṣe Nestle Nigeria Plc n beere fun iwe-ẹri aṣeyege akọkọ lọdọ Ajọ to n ri si lilo omi lọna to dara ju lọ lagbaaye (AWS) ti ipele 2.0 lori awọn agbekalẹ wọnyi:
Ileeṣẹ: Nestle Nigeria Plc., Agbara
Adirẹsi Ileeṣẹ: Klm 32, Lagos-Badagry Expressway, Agbara Industrial Estate, Agbara.
Nọmba AWS: AWS 000100
Ọjọ ayẹwo: 9-10 December 2021
Eto ayẹwo: Lati okeere wa
Agbegbe ayẹwo: Oju kan naa
Iru ayẹwo: Ti iwe-ẹri akọkọ
Abẹwo aridaju fun ifunni-niwee-ẹri akọkọ yoo waye ni ọjo kẹsan-an si ọjọ kẹwaa, oṣu kejila, 2021. Nitori ajakalẹ arun Covid-19, ati ni ibamu si eto AWS, lati okeere wa ni wọn yoo ti maa ṣe awọn ayẹwo naa.
Ni ibamu si awọn alakalẹ lori ifunni-niwee-ẹri awọn AWS yii, gbogbo awọn ti ọrọ yii kan ni a n pe lati sọ ero wọn ranṣẹ lori ọrọ iwe-ẹri yii.
Bi o ba ṣe pe ẹ fẹẹ ba awọn igbimọ olubẹwo yii sọrọ, ẹ kan si olori awọn olubẹwo yii, ki oun le ṣeto ifọrọwerọ ori foonu pẹlu yin, tabi ti ori ẹrọ ayelujara. Ẹri gbọdọ wa fun iru adehun ifọrọwerọ bayii. Ọrọ yoowu ti kaluku ba si sọ, nnkan aṣiri la o fi i ṣe bi tọhun ba ti fẹ ẹ bẹẹ.
Fun ifọrọwerọ, tabi pe eeyan fẹẹ mu iwe apilẹkọ wa, ẹ kan si olori awọn olubẹwo yii. Ẹ le fi ọro yin ranṣẹ
*Lati ibi ifọrọwerọ okeere, ati/tabi
*Ki ẹ kọwe ẹ ranṣẹ
Olori awọn olubẹwo yii: Paula Gomez Geras
Ileeṣṣẹ to n ṣeto abẹwo naa: SGS
Email to jẹ ti olori awon olubẹwo: paula.gomezgeras@sgs.com
Nọmba tẹlifoonu olori awọn olubẹwo +34 636 296 427