Ondo ni wọn ti mu baale ile kan to pa iyawo rẹ ni Adamawa

Adewale Adeoye Ipinlẹ Ondo lawọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Adamawa ti pada mu baale ile kan, Ọgbẹni Riba Kwanta, ẹni ogoji ọdun to n gbe…

Ara kenge, obinrin yii gbe oku aburo baba rẹ lọ si banki lati fi ṣe oniduuro

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa agbegbe Rio de Janeiro, lorileede Brazil, ni iyaale ile kan, Abilekọ Erika De Souza Nunes,…

Sẹyin naa ti gbọ pe wọn ti gbe Bobrisky kuro ninu ọgba ẹwọn to wa

 Monisọla Saka Won Ti gbe gbajumọ jayejaye ọkunrin bii obinrin ori ayelujara nni, Idris Ọlarewaju Okunẹyẹ,…

Ile akọku ni Jamiu mu ọmọ ọdun mẹsan-an lọ n’llọrin, o si fipa ba a laṣepọ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọwọ ẹṣọ alaabo ṣifu difẹnsi ipinlẹ Kwara ti tẹ ọmọkunrin ẹni ọdun mọkandinlogun…

Lasiko ti awọn ọmoogun Yoruba Nation n fara han ni kootu lọwọ, eyi lohun ti Makinde ṣe fun Dupẹ Onitiri n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ti awọn ajijagbara Yoruba Nation ti dero ahamọ ọgba ẹwọn Agodi, n’Ibadan,…

O ma ṣe o! Ijamba ọkọ gbẹmi akẹkọọ Poli l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Dẹrẹba ọkọ kan to ti sa lọ bayii la gbọ pe o ṣokunfa…

Ile-ẹjọ fiwe ti yoo pọn ayẹwo ẹjẹ ọmọ Mohbad ni dandan ranṣẹ si Wumi

Faith Adebọla Ni bayii, dandan lowo-ori, ọran-an-yan laṣọ ibora, lọrọ ayẹwo ẹjọ Liam, da fun Wumi,…

O tan! Portable ko Olori Alaafin tẹlẹ, Queen Dami, sita bii ọmọ ọjọ mẹjọ

Monisọla Saka Gbajumọ olorin taka-sufee tẹnu ki i sin lara rẹ, Habeeb Okikiọla Ọmọ Ọlalọmi Badmus,…

Adeleke buwọ lu ami idanimọ tuntun fun ipinlẹ Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina Ademọla Adeleke ti buwọ lu ofin to ṣagbekalẹ ami idanimọ tuntun fun…

Ẹ la awọn araalu lọyẹ ki ẹ too maa mu wọn fun ẹsun ṣiṣe Naira baṣubaṣu-Oluwoo  

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Pẹlu bi ajọ to n gbogun ti ṣiṣe owo araalu baṣubaṣu, EFCC, ṣe…

Awọn tọwọ tẹ lori ọrọ ominira ilẹ Yoruba ti dero ọgba wọn 

Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, ọjọ marunlelọgọrun-un (105) lawọn afurasi ọdaran tọwọ tẹ lori iditẹgbajọba…