Aarẹ ilẹ Amẹrika ti korona kọlu sọ pe ara oun ti ya o

Aderounmu Kazeem

Lẹyin ọjọ diẹ ni ọsibitu, Aar oril-ede Amrika, Donald Trump, ti b bayii lọwọ arun koronafairọọsi to kọlu oun ati iyawo ẹ ni Fraidee, ọsẹ to kọja.

 Ni kete ti wn ti sọ fun un wi pe Ọlọrun ti ko o yọ lọwọ arun buruku to klu yii lo ti gba ori rọ abyfo  lọ, nibẹ lo si ti ba gbogbo awọn eeyan e sọrọ, to si fi wọn lọkan balẹ wi pe ara oun ti le daadaa, ati pe bi ara oun e ya lasiko yii, o fẹẹ maa ri bẹẹ lati bii ogun dun syin.

Lasiko ti ikede ipolongo ibo sipo aarẹ orile-ede Amẹrika n lọ lọwọ ni arun ọhun kọlu u, eyi to mu un fagile pupọ ninu awọn eto to ti la silẹ. Ṣugbọn ni bayii to ti bọ lọwọ arun Koro, Donald Trump yoo le t siwaju plu eto ipolongo r bayii.

Ninu ọrọ ẹ to sọ lo ti ni, “E ma e bru arun koro o, oril-ede wa ti ni idagbasoke to le koju  daadaa. Ijọba Donald Trump ti ṣiṣẹ takuntakun lati pese oogun to le koju arun ọhun, ati pe ọgbọn gidi n be fun wa pẹlu. Fun idi eyi,  ko gbd j ki arun kankan ko ipaya ba a yin, ijba Trump kaju  daadaa”

Leave a Reply