Adewọle Alao, onilu Ayinla Ọmọwura, ti ku o

Jide Alabi

Lẹyin bii ọjọ meloo kan ti awọn ẹgbẹ Ayinla Ọmọwura lori ẹrọ ayelujara ṣe imọyi fun un, ọkan pataki ninu awọn onilu Ayinla Ọmọwura nigba to wa laye, Adewọle Alao oniluọla, ti dagbere faye. Baba naa ku lẹni ọdun mẹtadinlọgọrun-un. A o maa mu ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa fun yin.

Leave a Reply