Alaga ẹgbẹ oṣelu Labour, Alaaji Abdulsalam, ti ku o

Faith Adebọla

 Alaga apapọ fun ẹgbẹ Labour Party, Alaaji Abdulkadir Abdulsalam, ti dagbere faye.  Owurọ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, ni wọn ni baba naa dakẹ nile rẹ, l’Abuja.

Igbakeji Akọwe apapọ fẹgbẹ ọhun, Kennedy Chigozie, to fidi iṣẹlẹ yii mulẹ sọ pe ẹgbẹ naa maa too ṣe ikede nipa iku ati isinku rẹ laipẹ.

Leave a Reply