Amosun, Akpabio kede atilẹyin fun Tinubu

Jọkẹ Amọri
Gomina ipinlẹ Ogun tẹlẹ ati ojugba rẹ ni ipinlẹ Akwa Ibom toun naa ti figba kan jẹ goimna ipinlẹ naa, Godswill Akpabio, ti ni awọn juwọ silẹ nibi ipo aarẹ, awọn si kede atilẹyin awọn fun ọkan ninu awọn oludije nilẹ Yoruba, Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu.

Leave a Reply