Loootọ ni wọn da Peter Obi duro ni London, eyi lohun to ṣẹlẹ-Onifade

Adewale Adeoye Ni bayii, ikọ eto iroyin ẹgbẹ oṣelu LP atawọn ololufẹ Peter Obi to dije…

Awọn alaṣẹ Fasiti Ifẹ fa afurasi to pa akẹkọọ ẹgbẹ rẹ nitori foonu le ọlọpaa lọwọ

Adewale Adeoye Nitori bi wọn ṣe lu akẹkọọ ẹgbẹ wọn, Okoli Ahize, pa nitori foonu ti…

Tirela sọ ijanu rẹ nu, lo ba ya bara wọnu mọṣalaṣi

Monisọla Saka Ori lo ko awọn abilekọ meji ati ọmọ-ọwọ kan yọ lọwọ iku ojiji pẹlu…

 Ẹ woju ọkan ninu awọn adigunjale to lọọ fọ ọja foonu l’Oke-Ilewo

Faith Adebọla Ọja igbalode kan to gbajumọ bii iṣana ẹlẹẹta l’Abẹokuta, nibi ti wọn ti n…

Awọn Fulani agbebọn ya wọ Agọ Igbira, l’Ọsun, wọn ji gende-kunrin kan lọ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn agbebọn ti wọn fura si bii Fulani ti ji ọmọkunrin ẹni ọgbọn…

Ọpọ eeyan ha sabẹ ile alaja meje to wo l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko  Ijamba iku ojiji tun ja bii iji niluu Eko l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kejila,…

Nitori foonu to ji, wọn lu akẹkọọ Fasiti Ifẹ pa

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Nitori foonu lasan, awọn janduuku kan ti lu akẹkọọ onipele to pari (Final…

N’Ileefẹ, Muideen fi oogun oorun sinu ounjẹ fawọn ọmọbinrin mẹrin, ilu Kano ni wọn ti laju

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọkunrin kan, Muideen Adebisi, yoo rojọ, ẹnu rẹ yoo fẹrẹ bo lagọọ ọlọpaa…

Lati maa jiyin iṣẹ iriju rẹ, Gomina Adeleke yoo bẹrẹ ipade ẹẹkan loṣu mẹrin pẹlu araalu

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke, ti kede pe oun yoo bẹrẹ ipade…

Awọn ọmọ yahoo mẹrin rẹwọn he, igbo ni wọn n fa lotẹẹli kan ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kọkanla, oṣu Kẹrin, ọdun yii, ni adajọ ile-ẹjọ Majisireeti…

Awọn agbebọn ya wọlu, wọn paayan, wọn tun ji awọn mi-in gbe lọ

Awọn agbebọn tẹnikan ko mọ ti ya wọnu abule Gangarbi, to wa nijọba ibilẹ Rano, nipinlẹ…