Awọn ọlọpaa gba mọto lọwọ mi lọna eru, wọn si ta a fun ọkan lara wọn – Kọlawọle

Florence Babaṣọla   Ọgbẹni Elusanmi Kọlawọle fara han niwaju igbimọ to n ṣewadii iwa awọn ọlọpaa…

Akẹkọọ fasiti Al-Hikmah lẹdi apo pọ pẹlu agunbanirọ lati ja ileewe naa lole miliọnu mẹsan-an naira

Stephen Ajagbe, Ilorin Akẹkọọ kan to wa nipele 400Level, ni fasiti Al-Hikmah, niluu Ilọrin, Idris Shuaibu…

Ọlọpaa meji padanu ẹmi wọn ninu ijamba ọkọ lọna Ilọrin si Ogbomọṣọ

Stephen Ajagbe, Ilorin   Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, nijamba ọkọ gbẹmi ọlọpaa meji lagbegbe Ẹyẹnkọrin, lọna…

Wasiu Ayinde, gbajugbaja onifuji, ti ku o

Ọlawale Ajao, Ibadan   Agba ọjẹ lagbo ere Fuji, Alhaji Wasiu Salawudeen Gbọlagade Ayinde, ti jade…

Awọn agbanipa yinbọn fun Ridwan Oyekọla, ọmọ Yorùbá to mọ ẹ̀ṣẹ̀ ẹ já jù lagbaaye

Ọlawale Ajao, Ibadan   Ori lo ko abẹ́ṣẹ́-kù-bíi-òjò nni, Ridwan Oyekọla, ọdọmọde to n ṣoju orileede…

Awọn adigunjale fọ banki niluu l’Okuku, wọn kowo nla lọ

Florence Babaṣọla   Lọwọlọwọ bayii, awọn ọlọpaa ati ọmọ ẹgbẹ OPC ti n dọdẹ awọn adigunjale…

Dokita yii n rin ni bebe ẹwọn o, mita ina lo ji l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla       Dokita kan ati ọmọọṣẹ rẹ ti wọn fẹsun kan pe wọn…

Hijaabu: Ijọba yi ipinnu rẹ pada, o ni kawọn ileewe mẹwaa ṣi wa ni titi n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin   Nitori wahala tọrọ lilo ibori ta a mọ si hijaabu laarin awọn…

Wọn ti dajọ iku fun Ibrahim to ge ori ọmọ ọdun meji l’Owode-Ẹgba

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Ile-ẹjọ giga ipinlẹ Ogun ti dajọ iku fun Ibrahim Muhammed, ẹni ọdun…

Ẹyin Fulani, ẹ yee gbe ninu igbo, ẹ maa bọ nigboro-Oluwoo

Florence Babaṣọla   Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti fẹsun kan awọn aṣaaju…

Kọlawọle n lọ ṣẹwọn gbere l’Akurẹ, awọn ọmọleewe keekeeke mẹrin lo fipa ba lo pọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ       Adajọ Ile-ẹjọ giga kan l’Akurẹ ti dajọ ẹwọn gbere fun…