Fayẹmi ṣebura fawọn kọmiṣanna ati oludamọran tuntun

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Gomina Kayọde Fayẹmi tipinlẹ Ekiti ti ṣebura fawọn kọmiṣanna mẹjọ ati oludamọran pataki…

Abraham lu Fulani pa l’Ogboomọṣọ, o lo fi maaluu jẹ oko oun

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori ti Fulani fi maaluu jẹ oko ẹ, ọkunrin agbẹ kan, Abraham Alamu, ti lu…

Jimoh Ibrahim darapọ mọ ẹgbẹ APC l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akure Ọgọọrọ awọn ọmọ ẹgbẹ APC loriẹ-ede yii ni wọn peju peṣẹ siluu Igbotako,…

Ijamba ọkọ ajagbe elepo fẹmi ọpọ eeyan ṣofo l’Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Eeyan mẹrin ni wọn pade iku ojiji, ti ọpọ eeyan si tun fara pa nibi…

Ijọba Eko yoo ṣi ileewe alakọọbẹrẹ ati girama lọjọ kọkanlelogun, oṣu kẹsan-an

Faith Adebọla Idunnu ti ṣubu lu ayọ fawọn akẹkọọ lawọn ile-ẹkọ jake-jado ipinlẹ Eko pẹlu bi…

Wahala de, awọn meji di alaga PDP l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Walaha to n lọ lọwọ lẹgbẹ oṣelu People’s Democratic Party nipinlẹ Ekiti ko…

Ẹ fi papa iṣere Ilọrin sọri Rashidi Yẹkini- Pinnick

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lọna ati bu ọla fun ogbontarigi agbabọọlu ilẹ wa to ti doloogbe, Rashidi…

O ṣẹlẹ, kọmiṣanna kọwe fipo silẹ ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Lẹyin ọsẹ kan ti oludamọran pataki feto ilera, Ọjọgbọn Wale Suleiman, kọwe fipo rẹ…

Ipinlẹ Ekiti yoo bẹrẹ ayẹwo fawọn to fẹẹ darapọ mọ ikọ Amọtẹkun lọjọ Aje

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ijọba ipinlẹ Ekiti, nipasẹ igbimọ to n ṣakoso ikọ Amọtẹkun, yoo bẹrẹ ayẹwo…

Ẹwọn ọdun mẹwaa ladajọ ju Bọlanle si ni Sokoto

Oluyinka Soyemi, Ado-EkitI Idajọ ẹwọn ọdun mẹwaa gbako ni ọkunrin kan, Bọlanle Adefẹmiwa, gba nipinlẹ Sokoto…

Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (14)

Awọn ọrọ ti mo n sọ wọnyi, mo fẹ ka ṣe akọsilẹ ati afọkansi wọn daradara.…