Eroja ara faanu ti Rasheed ji l’Oṣogbo ti sọ ọ dero ọgba ẹwọn

Florence Babaṣọla Rasheed Kọla, ọmọ ọdun mẹẹẹdọgbọn ni awọn ọlọpaa ıpinlẹ Ọṣun ti gbe lọ sile…

O ku oṣu kan ki Wuyi ṣegbeyawo lo ku sori aṣẹwo l’Ekoo

Ọmọkunrin ẹni ọdun mejilelọgbọn kan, Wuyi Jackson to n wa ọkọ epo, ti gba ibi to…

Adeshina di Aarẹ banki idagbasoke Afrika lẹẹkeji

Oluyinka Soyemi Ọmọ ilẹ wa, Akinwumi Adeshina, ti wọle lẹẹkeji gẹgẹ bii Aarẹ banki idagbasoke ilẹ…

Wọn mu Lekan pẹlu ọkọ to ji gbe l’Owode-Ẹgba, lo ba loun ko ti i ji ju mọto mẹta lọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi awọn mọto mẹta kan yoo ṣe di riri pada ni awọn ọlọpaa…

Gbogbo ọna abalaye la maa lo lati ṣawari awọn to pin owo tawọn adigunjale ji gbe l’Okeeho

Olu-Theo Ọmọlohun, Oke-Ogun Onjo tilu Okeho, Ọba Rafiu Oṣuọlale Mustapher, ti sọ ni gbangba pe gbogbo…

Sunday to n paayan l’Akinyẹle ni: Mo tun lọọ paayan kan lẹyin ti mo sa jade lahaamọ (Fidio)

Ohun to fa wahala lasiko ibo ti wọn di ni 1964 niyi o (6)

Nigba ti yoo fi to bii aago mẹwaa aabọ ni ọjo kin-in-ni, oṣu kin-in-ni, ọdun 1965,…

Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979 (8)

*Idi abajọ ree o Ko ju oṣu meji ti Ọgagun Muritala Muhammed gba iṣẹ gẹgẹ bii minisita…

Ibo aarẹ 2023: Tinubu ati Fayẹmi wọ ṣokoto ija

Bi kinni kan ba wa to wu Gomina ipinlẹ Ekiti laye yii ju lọ, ipo aarẹ orilẹ-ede Naijiria…

Eto isinku Bamidele Olumilua bẹrẹ, oku oloogbe kọja si Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Gomina ipinlẹ Ekiti, Kayọde Fayẹmi, ti gba oku Gomina Ondo atijọ, Bamidele Olumilua,…

Abdullahi dero kootu, iya arugbo ni wọn lo lu n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla Abdullahi Salisu, ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn, ti n kawọ pọnyin ni kootu Majisreeti kan niluu…