O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Kin ni wahala Lai Muhammed yii gan-an? Ko si ki eeyan ma beere pe kin ni wahala Bọọda Lai Muhammed.…

Baba ti wọn lo fun tẹgbọn-taburo loyun ni awọn obi wọn mọ si i (Fidio)

Mary sa pamọ l’Ekiti, lo ba tẹ atẹjiṣẹ sawọn obi ẹ pe wọn ji oun gbe ni  

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti tẹ ọmọdebinrin ti ko ti i to…

Akeem ọlọkada to ta tẹtẹ lawin l’Oṣogbo ti foju bale-ẹjọ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọkunrin ọlọkada kan, Akeem Jimoh, lawọn ọlọpaa ti wọ lọ si kootu Majisreeti…

Abiọna lu oyinbo ni jibiti, wọn ti sọ ọ sẹwọn ọdun meji n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọdaran kan, Abiọna Akinyẹmi Festus, tọwọ EFCC tẹ laipẹ yii fẹsun jibiti ori…

Awọn ọmọọta fi ororo gbigbona wẹ Qudus nitori ko fun wọn ni pọfupọọfu ọfẹ

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ko si beeyan ṣe jẹ ọdaju to, ti onitọhun ba ri ọdọmọkunrin ẹni…

Atunṣe bẹrẹ nileewosan ilu Ọttẹ lẹyin aṣẹ Gomina Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Nitori ipo to buru jai tileewosan alaboyun ijọba to wa niluu Ọttẹ wa,…

Awọn aṣọbode yinbọn pa awakọ epo, lawọn ọdọ ba fibinu pa ọga wọn ni Ṣaki

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Wahala ati idarudapọ ti ko kere lo ṣẹlẹ lọsan-an Ọjọbọ, Tọsidee to kọja yii, lakooko tawọn oṣiṣẹ ileeṣẹ…

Eyi ni bi awọn Fulani to ji mi gbe ni Lanlatẹ ṣe pa ọkọ afẹsọna mi

Obinrin oniṣowo kan, Modupẹoluwa Oyetọṣọ, wa ninu ọfọ iku ọkọ afẹsọna rẹ lọwọlọwọ bayii, adanu naa…

Ọpẹ o, wọn ti pari ija obinrin toju ẹ yatọ ni Kwara atọkọ ẹ

Stephen Ajagbe, Ilorin Iroyin ayọ to tẹ wa lọwọ laaarọ oni ni pe ija to wa…

Ridwan ha sọwọ ọlọpaa, ọjọ ọdun Ileya lo figi paayan ni Ṣagamu

Adefunkẹ Adebiyi, Abeọkuta Lọjọ ọdun Ileya to kọja yii ti i ṣe ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu keje,…