LASTMA ri ibọn ninu ọkọ ayọkẹlẹ ti wọn mu pe o ṣẹ sofin irinna l’Ekoo

Monisọla Saka L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kẹrinlelogun, oṣu Kọkanla ọdun yii, ni Ajọ to n ri si…

Alawada ni oṣiṣẹ to ba gba ipo tuntun lọwọ Oyetọla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti bura fun awọn oṣiṣẹ ijọba ọgbọn…

Lẹyin tawọn eleyii pa ọga olotẹẹli n’Ijẹbu, wọn tun fẹẹ jiyawo atọmọ ẹ gbe

Gbenga Amos, Abẹokuta  Bi wọn ba leeyan ya ika, afibi-ṣoloore ati ọdaju, gbogbo ẹ lo pe…

Awọn aṣofin Eko sunkun gidigidi nibi eto idagbere fun ọkan ninu wọn to ku si Jos

Faith Adebọla, Eko  Yoruba bọ, wọn ni lọjọ a ku la a dere, eeyan o sunwọn…

Bi wọn ba n tan Oyetọla, koun naa ma tan ara rẹ o jare

Ko si ohun to jẹ tuntun ninu ki awọn kan jokoo sibi kan ki wọn maa…

Ọkọ oju omi kankan ko gbọdọ ṣiṣẹ lẹyin aago meje alẹ – Ijọba Eko

Monisọla Saka Pẹlu ba a ṣe n wọnu pọpọṣinṣin ọdun lọ yii, ijọba ipinlẹ Eko ti…

Atiku yoo ṣepade pẹlu awọn gomina marun-un tinu n bi ninu ẹgbẹ wa laipẹ -Okowa

Monisọla Saka Irọ pata ni pe ẹgbẹ wa ti fẹnu ko lati le awọn gomina ẹgbẹ…

Aworan mi ni awọn alatilẹyin Aṣiwaju n gbe kiri ti wọn n pe ni Tinubu -Donald Duke

Lọla Ojo Gomina ipinlẹ Cross Rivers tẹlẹ, Donald Duke, ti kegbare pe aworan oun ni awọn…

Gbogbo eyi ti a n wi dun, ẹ tọju Tinubu o!

Fidio kan n ja ran-in ran-in kaakiri ilẹ yii bayii, iyẹn fidio kan ti Gomina ipinlẹ…

Wọn ni Wolii Alade-Ẹmi lo fun ọmọ iya ijọ wọn to ku ni majele jẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Afi ki gbogbo mọlẹbi atawọn ti wọn ba fẹran ọkunrin kan ti wọn…

O ga o! Wọn fẹẹ fi ida ṣa Peter Obi pa lasiko ipolongo ẹ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ori lo ko oludije fun ipo aarẹ orileede yii labẹ ẹgbẹ oṣelu Labour…