‘Eyi lohun tawọn Fulani ajinigbe foju mi ri’

Jọkẹ Amọri Ko si ariyanjiyan mọ bayii pe awọn ajinigbe ati afẹmiṣofo ti wọn jẹ ọmọ…

 Ọbasanjọ ṣekilọ: Boko Haram ọjọ ọla lawọn ọmọ ti ko lọ sileewe

Monisọla Saka Olori orilẹ-ede wa nigba kan, Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti ṣekilọ fun ijọba Naijiria pe ti…

Ibalopọ lo dija silẹ, l’Ọdunayọ ba fibinu gun ọkọ ẹ pa

Ọlawale Ajao, Ibadan Gba fun mi, n ko gba fun ọ, yunkẹ yunkẹ ti ọkunrin kan…

Awọn ajinigbe yari, wọn lowo tuntun ti wọn ṣẹṣe paarọ lawọn yoo gba fowo itusilẹ

Adewumi Adegoke Afi ki onikaluku wọle adura bayii pe k’Ọlọrun maa ṣọ wa o, ka ma…

Ko si iwe-ẹri Adeleke lọdọ wa o – INEC Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Kọmiṣanna fun ajọ eleto idibo nipinlẹ Ọṣun, Dokita Mutiu Agboke, ti sọ fun…

Oogun lawọn eleyii fi ba iya arugbo sọrọ ti wọn fi gbowo nla lọwọ rẹ

Faith Adebọla, Eko Mama agbalagba ẹni ọdun mẹrinlelọgọta kan lo sare wọ banki rẹ lọ lọjọ…

Wahala niluu Ikirun: Wọn yinbọn pa  omọọba, wọn tun dana sun aafin  

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Niṣe lọrọ di bo o lọ o yago niluu Ikirun Agunbẹ onilẹ obi,…

Wọn ti mu mẹrin ninu awọn ajinigbe to n da wọn laamu nipinlẹ Ogun

Faith Adebọla, Ogun Ẹni ọdun mọkanlelogun pere ni Ismaila Ibrahim, oun lọjọ-ori ẹ kere ju lọ…

Olori awọn aṣofin Ekiti ti wọn yọ nipo gba kootu lọ

Adewumi Adegoke Ko jọ pe wahala to n ṣẹlẹ nileegbimọ aṣofin ipinlẹ Ekiti, nibi ti won…

Aarẹ Buhari ṣafihan owo Naira tuntun

Faith Adebọla Gbogbo ẹyin tẹ ẹ ba lowo Naira nile, afi kẹ ẹ ma jafara bayii…

‘Loootọ ni, awa la pa ọrẹ wa, igba Naira la ta ẹya ara rẹ fun babalawo’

Gbenga Amos, Ogun Ọrẹ o si mọ, ka rẹni ba rin lo ku, ọrọ yii ti…