Awọn agbebọn to ji aafa at’ọmọ ẹ n’Ilọrin n beere fun ọgọrun-un kan miliọnu 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn agbebọn to ji Aafa Sọfiu, ọmọ rẹ ati ẹnikan torukọ rẹ n…

Awa jagunjagun ibilẹ le daabo bo ilu wa ju awọn agbofinro ijọba lọ-Ọmọluabi

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori eto aabo to mẹhẹ lorileede yii, paapaa, nitori laasigbo ti ẹya ajeji n da…

Awọn gomina PDP marun-un faake kọri: A o ni i ṣiṣẹ fun Atiku o

Faith Adebọla, Eko Ẹkọ o ti i ṣoju mimu ninu ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP,…

Sidika tọju kokeeni sinu bata to n wọ lọ si Mẹka

Monisọla Saka, Eko Ọwọ ṣinkun ajọ to n gbogun ti iwa gbigbe oogun oloro nilẹ wa, National Drug Law Enforcement Agency (NDLEA), ti tẹ obinrin opo ẹni ọdun…

2023: Tinubu jafafa, o si ni iriri lati gbe orileede yii goke agba – Oyetọla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ti awọn ọmọ orileede yii ba le dibo fun oludije funpo aarẹ labẹ…

Adigunjale kọ lẹta si wọn laduugbo Ologunẹrun, n’Ibadan, wọn lawọn yoo ba wọn lalejo nipari oṣu yii

Ọlawale Ajao, Ibadan Inu ibẹrubojo ni awọn eeyan adugbo Ifẹlagba, Adetokun, Ologun Ẹru, to wa ni…

Awọn gomina ẹgbẹ PDP marun-un (G-5) wọle ipade l’Ekoo

Faith Adebọla Ba a ṣe n kọ iroyin yii, ipade pataki kan n lọ lọwọ laarin…

Oore nla de fun Iyabọ Ojo, Jaiye Kuti ati Bọsẹ Akinọla

Lọla Ojo Beeyan ba gẹṣin ninu awọn oṣere ilẹ wa mẹta kan, o daju pe tọhun…

Aye le o! Lẹyin ti ọga Zainab fipa ba a lo pọ tan lo ni ki wọn lọọ pa a 

Gbenga Amos, Ogun Ọga telọ, to lawọn ọmọ ẹkọṣẹ lọkunrin lobinrin lọdọ ni Sulaimon Oriọla, niluu…

Wahala n’Igboọra, Jamiu yinbọn paayan nitori tikẹẹti ọkada, ni wọn ba dana sun un

Gbenga Amos, Abẹokuta Titi di ba a ṣe n sọ yii ni ilu Igbo-Ọra, to wa…

Yinusa ti jẹwọ: Loootọ ni mo ji ọkada, ṣugbọn ẹ ṣaanu mi

Gbenga Amos, Abẹokuta Akolo ọlọpaa, lẹka ileeṣẹ wọn to wa niluu Ipokia, nijọba ibilẹ Ipokia, ipinlẹ…