Awọn agbebọn to ji iya atawọn ọmọ rẹ gbe ni Kwara n beere fun ọgọrun-un miliọnu

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Afi bii ewurẹ ti wọn ni ki i ṣiwọ to ba tẹnu bọ…

 Tayelolu pa ọkọ rẹ l’Ondo, ọmọ odo lo la mọ ọn lori to fi ku

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn ọlọpaa ipinlẹ Ondo ṣi…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ laarin Funkẹ Akindele ati baba awọn ọmọ rẹ

Faith Adebọla Ọpọ igba lo jẹ pe tawọn tọkọ-taya kan ba ti pin gaari, ti wọn…

Eyi ni bi ọba awọn ọmọ Igbo n’Ibadan ṣe toju oorun doju iku

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọba awọn Igbo nilẹ Ibadan, ati nipinlẹ Ọyọ, Ọmọwe Alex Anozie, ti jade laye.…

Nitori bo ṣe ta awọn dukia ijọba, awọn eeyan Ọyọ kan n binu si Makinde

Ọlawale Ajao, Ibadan Tọmọde tagba nilẹ Ibadan ti parọwa si Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde,…

‘Ẹbun miliọnu mẹwaa Aaira lo wa fun iyawo Mohbad bayẹwo ẹjẹ ba sọ pe ọmo ọwọ rẹ ti oloogbe ni’

Adewale Adeoye Ni bayii, oludasilẹ ileeṣẹ tẹlifiṣan igbalode kan ti wọn n pe ni ‘African television’ Ọgbẹni Larry Omodia loun maa ṣeto ẹbun owo miliọnu mẹwaa…

Ile-ẹjọ lawọn aṣofin Ondo ko gbọdọ yọ Igbakeji gomina wọn

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Adajọ ile-ẹjọ giga kan to filu Abuja ṣe ibujokoo, Onidaajọ Emeka Nwite, ti…

‘Ẹ ma gbe oku Mohbad wa s’Ikorodu mọ o’

Olubukọla Ganiu Pẹlu ikanra ati ibinu, ni gendekunrin to jẹ ọkan lara awọn ọmọ Ikorodu ti…

 Asẹyin tuntun ti wọ ipẹbi lọ fun etutu ọba

Ọlawale Ajao, Ibadan Lasiko ta a n kọ iroyin yii, Ọmọọba Ṣẹfiu Ọlawale Oyebọla, Asẹyin tilu…

A fara mọ bi Peter Obi ṣe lọ si ile-ẹjọ to ga ju lọ-Ẹgbẹ Afẹnifẹre

Adewale Adeoye Ẹgbẹ Afẹnifẹre ilẹ wa ni ko sohun to le yi ipinu awọn pada lori atilẹyin…

Ẹ ra ounjẹ to pọ sile o: Ẹgbẹ oṣiṣẹ kede iyanṣẹlodi ọlọjọ gbọọrọ

Jamiu Abayọmi Agbarijọpọ ẹgbẹ oṣiṣẹ ilẹ wa, Nigeria Labour Congress, (NLC) ati Trade Union Congress, (TUC…