Ismail Adeẹyọ Yoruba bọ, wọn ni ‘ọmọ iya ki i ya, ọmọ baba ni i ba’,…
Author: admin123
Ki i ṣe dandan mọ ki aarẹ orileede yii lọọ maa gbatọju loke-okun-Aisha Buhari
Adewale Adeoye ‘Pẹlu ohun to wa nilẹ yii, inu mi dun gidi pe ki i ṣe…
Ẹwọn n run nimu Dada yii o, apo igbo kan ni wọn ka mọ ọn lọwọ l’Ado-Ekiti
Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti wọ ọkunrin ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn kan, Lasisi Dada,…
NDLEA mu afurasi ọdaran mẹrinlelọgbọn to n ṣowo egboogi oloro
Adewale Adeoye Ajọ to n gbogun ti lilo ati gbigbe egboogi oloro nilẹ yii, ‘National Drug…
Kootu ju Sani sẹwọn oṣu mẹta, ẹni to ṣoniduuro fun lo sa lọ
Adewale Adeoye Ko sẹni to ri baba agbalagba kan, Sani Ukasha, ẹni ọdun mọkanlelọgbọn to n…
Oṣere-binrin yii sunkun kikoro nitori bi ọkunrin onitiata kan ṣe lu u nilukulu
Monisọla Saka Ọkan ninu awọn onitiata ilẹ wa lobinrin to ṣẹṣẹ n goke bọ, Temitayọ Morakinyọ,…
Nibi ti wọn ti n ja nitori ọmọge, Marvelous fi siṣọọsi gun aladuugbo rẹ pa l’Ọka Akoko
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ile-ẹjọ Majisireeti to wa l’Oke-Ẹda, niluu Akurẹ, ti ni ki ọmọkunrin ẹni ọdun…
Nitori ti wọn ko fẹ ko lọ sile, awọn ọlọpaa tun sare gbe Ṣeun Kuti pada lọ si kootu
Monisọla Saka L’Ọjọbọ Tọsidee, ọjọ kejidinlogun, oṣu Karun-un, ọdun yii, lawọn ọlọpaa tun gbe Ṣeun Kuti,…
Iba dara to ba jẹ pe bii ogun ọdun sẹyin ni Tinubu dupo aarẹ- Peter Obi
Monisọla Saka Peter Obi, ti i ṣe oludije dupo aarẹ lẹgbẹ oṣelu Labour Party, sọ pe…
Nitori ti wọn tapa sofin imọtoto ayika, eeyan mẹfa rẹwọn he ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kejidinlogun, oṣu Karun-un, ọdun yii, ni kootu alagbeeka kan niluu…
A ti na to igba biliọnu Naira fun ipalẹmọ eto ikaniyan ti ko waye mọ yii-NPC
Adewale Adeoye Ajọ eleto ikanniyan lorileede wa, ‘National Population Commision’ (NPA), ti sọ ọ di mimọ…