O ga o, igbeyawo awọn oṣere yii ti daru

Jọkẹ Amọri Looootọ lo ti pẹ ti awọn eeyan ti n gbe e pooyi ẹnu pe…

Eyi lọrọ ti Adedoyin sọ lẹyin ti adajọ dajọ iku fun un

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Loootọ ni owe Yoruba maa n sọ pe akọ igi ko gbọdọ soje,…

Owo iranwọ epo ni yoo rẹyin Naijiria ta o ba tete fopin si i – Shettima

Monisọla Saka Igbakeji Aarẹ orilẹ-ede yii, Sẹnetọ Kashim Shettima, ti fawọn ọmọ Naijiria lọkan balẹ pe…

Nitori ti wọn de epo mọlẹ, ijọba Kwara ti awọn ile-epo kan pa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọgbọnjọ, oṣu Karun-un yii, ni ijọba ipinlẹ Kwara, labẹ iṣejọba…

Nitori bata lasan, ọrẹ meji gun Ekene lọbẹ pa n’Iganmu

Faith Adebọla Loootọ lawọn agba sọ pe ariyanjiyan ni i ba ọrẹ jẹ, amọ bo ba…

Ibọn ogoji, ọta rẹpẹtẹ, ada ati oogun abẹnugọngọ lawọn ọlọpaa ko nile Auxilliary

Ọlawale Ajao, Ibadan Titi di ba a ṣe n sọ yii ni awọn ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ…

O ma ṣe o, wọn ba oku iya pẹlu awọn ọmọ rẹ meji ninu ṣọọbu

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Eko ti sọ pe iwadii ti bẹrẹ lati mọ ohun to…

O di ipari oṣu Kẹfa ka too yọ owo iranwọ epo bẹntiroolu- Tinubu

Adewale Adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Tinubu ti tan imọlẹ sọrọ to sọ ni gbara…

Lẹyin ti Makinde yọ Auxillary nipo, awọn ọmọ ẹ n da igboro ru n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bi gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti tu igbimọ to n dari awọn awakọ…

Iku Timothy: Adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun Adedoyin titi ti ẹmi yoo fi bọ lara rẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Onidaajọ Adepele ti paṣẹ pe ki wọn yẹgi fun Dokita Rahman Adedoyin titi…

Ile-ẹjọ ni loootọ ni Adedoyin lọwọ ninu iku Timothy Adegoke

Florence Babaṣọla, Oṣogbo   Beeyan ba ju abẹrẹ silẹ, ketekete ni yoo maa gbọ ohun abẹrẹ…