Adewale Adeoye Awọn alaṣẹ ilu Atani, nijọba ibilẹ Ogbaru, nipinlẹ Anambra, ti foju Ọgbẹni Albert Eligbue,…
Author: admin
Ọwọ EFCC tẹ ọmọ Yahoo mẹjọ, eyi lawọn nnkan ti wọn ba lọwọ wọn
Adewale Adeoye Mẹjọ lara awọn ọmọ Yahoo kan ti wọn n ṣe gbaju-ẹ lori ẹrọ ayelujara…
Ile-ẹjọ ni kiyawo to fẹẹ kọ ọkọ ẹ sile da owo-ori to gba pada fun un
Adewale Adeoye A ki i jẹ meji laba Alade ni adajọ ile-ẹjọ Sharia kan, Onidaajọ Malam…
Ẹni kan ku, ọpọ fara pa, nibi ija ẹṣọ Amọtekun atawọn Hausa l’Atikankan
Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lasiko ijaagboro to waye fun bii wakati kan aabọ gbako laarin ẹṣọ Amọtẹkun…
Ẹni kan ku, ọpọ fara pa nibi ija ẹṣọ Amọtekun atawọn Hausa l’Atikankan
Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lasiko ijaagboro to waye fun bii wakati kan aabọ gbako laarin ẹṣọ Amọtẹkun…
Ẹẹmeji ni mo ti ba wọn kopa ninu ijinigbe, a ko ti i r’owo gba tẹni ta a ji fi ku sọdọ wa-Akinyẹmi
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹẹmeji ni mo ti ba wọn kopa ninu ijinigbe, a ko ti i…
Tinubu ti tun tẹkọ leti lọ siluu oyinbo, eyi lohun to n lọọ ṣe
Monisọla Saka Aarẹ tuntun ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan lorilẹ-ede Naijiria, Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu, ti…
Buhari be awọn asofin, ẹ jọwọ, ẹ fọwọ sí ẹgbẹrin milionu dola ti mo fẹẹ ya
Monisọla Saka L’Ọjọruu Wẹsidee, ọjọ kẹwaa, oṣu Karun-un, ọdun yii, ni Aarẹ orilẹ-ede Naijiria, Muhammadu Buhari,…