Ibi tawọn ajagungbalẹ mẹta yii ti n yinbọn mọ araalu n’Igbẹsa lọlọpaa ti ko wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Loootọ ni wọn n’iku ogun ni i pa akinkanju, ṣugbọn Afaimọ ni ijagungbalẹ…

O ma ṣe o! Ẹni kan ku, ọpọ fara pa, nibi ijamba ọkọ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ẹni kan ku, ọpọ fara pa, nibi ijamba ọkọ kan to waye lopopona…

Nitori oju ọna to bajẹ kọja sisọ, ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ fẹhonu han, wọn di marosẹ Eko si Abẹokuta pa

Faith Adebọla, Eko Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ, ẹka tipinlẹ Eko ati Ogun, ti ṣediwọ fun lilọ bibọ…

Ẹgbẹ Afẹnifẹre taku: Afi ka jokoo lati jiroro lori ibagbepọ wa bii orileede

Faith Adebọla, Eko Ẹgbẹ to n ja fun iṣọkan ọmọ Yoruba, Afẹnifẹre, ti sọ pe inu…

Buhari tun fẹẹ ya igba miliọnu dọla, wọn lawọn fẹẹ fi ra àwọ̀n ap’ẹ̀fọn

Faith Adebọla Lọtẹ yii, awọn aṣofin apapọ ti koro oju si ibeere ijọba apapọ pe ki…

Eyi ni idi ti Fayẹmi ko fi si nibi abẹwo tawọn gomina ilẹ Yoruba ṣe si Tinubu-Akeredolu

Jọkẹ Amọri Lati bomi pana ahesọ ti awọn kan n gbe kiri pe ija buruku n…

Nitori Sunday Igboho, Gumi sọko ọrọ sawọn aṣaaju ẹsin ilẹ Yoruba

Faith Adebọla Ilumọ-ọn-ka aṣaaju ati olukọ ẹsin Islam l’Oke-Ọya nni, Sheik Ahmed Abubakar Gumi, ti takoto…

Awọn oṣiṣẹ-fẹyinti ṣewọde l’Oṣogbo, wọn ni ki Gomina Oyetọla san owo awọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lati agbegbe Old Garage, lawọn oṣiṣẹ-fẹyinti nipinlẹ Ọṣun ti gbera laaarọ ọjọ Iṣẹgun,…

Awọn gomina ilẹ Yoruba ṣepade bonkẹlẹ niluu Eko

Faith Adebola Irọlẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, lawọn gomina lati ilẹ Yoruba ṣepade bonkẹlẹ nile…

Awọn araalu binu dana sun ọkọ, iyawo at’ọmọ wọn, wọn ni wọn n ṣagbodegba fawọn ajinigbe

Faith Adebọla  Iṣẹ bonkẹlẹ ni iṣẹ ami ṣiṣe, iṣẹ naa ni wọn fẹsun kan baale ile…

N ko ti i mọ oludije fun’po gomina Ọṣun lọdun to n bọ, ṣugbọn mo mọ pe ẹgbẹ wa maa wọle pada – Bisi Akande

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alaga akọkọ fun ẹgbẹ oṣelu APC lorileede yii, Oloye Bisi Akande, ti sọ…