Ile Arugbo: Ile-ẹjọ ti ni ijọba Kwara le kọle sori ilẹ awọn Saraki o

Stephen Ajagbe, Ilorin L’Ọjọbọ, Tọsidee, oni yii, ni ile-ẹjọ giga kan ni ipinlẹ Kwara ti fun…

Ẹ wo Victor Agunbiade, Ọmọ Yoruba to gbe orukọ Naijiria ga l’Amẹrika

Nibi ti awọn kan ti wa ti wọn ko ni iṣẹ meji ju ki wọn ba…

 Ẹ wo Baalẹ to n ba ọmọ bibi inu ẹ sun l’Owode-Yewa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lẹyin ọdun kẹrin to ti n ba ọmọ bibi inu ẹ to jẹ…

Adams di alaga ẹgbẹ PDP l’Ondo

Nibi idibo ẹgbẹ oṣelu PDP ipinlẹ Ondo to waye lonii niluu Akurẹ, nipinlẹ Ondo, ni awọn…

Eyitayọ Jẹgẹdẹ ṣabẹwo si Mimiko l’Ondo

Ni nnkan bii aago mẹjọ alẹ ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni oludije sipo gomina ninu…

Bamgboye ku lojiji nitori jibiti miliọnu marun-un ti Peter lu oun atiyawo ẹ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Peter Gbese, ẹni ọdun mẹtadinlogoji (37), ki i ṣe ọmọ Naijiria, ilẹ Olominira…

Awọn dokita lugbadi arun Korona lọsibitu ijọba n’Ibadan, ni wọn ba ti i pa

Ọlawale Ajao, Ibadan Itankalẹ kokoro arun Korona tun bọna mi-in yọ lanaa pẹlu bi awọn dokita,…

Nitori gbese, Abiọdun fẹẹ bẹ sinu ọsa lọjọ ọdun, o ni ki omi kuku gbe oun lọ

Bi ko je awon ọlọpaa Eko ti won wa nitosi, eyi ti a n wi yii…

FA Cup: Arsenal gbo ewuro soju Chelsea

Ẹgbẹ agbabọọlu Arsenal ilẹ England ti fagba han alatako wọn, Chelsea, ninu aṣekagba FA Cup to…

Sanwo-Olu paṣẹ pe kawọn ileejọsin di ṣiṣi lati ọjọ keje, oṣu yii, l’Ekoo

Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Sanwo-Olu ti paṣẹ pe lati ọjọ keje, oṣu yii, ki awọn ileejọsin…

Awọn ọmọ iya meji ṣọdun Ileya latimọle, maaluu ni wọn ji gbe l’Ogbomọṣọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Bi gbogbo Musulumi kaakiri agbaye ṣe n dunnu, ti wọn yọ, lasiko ọdun…