Lori ọrọ agbofinro ti wọn le nitori o loyun, ijọba Ekiti gbe ileeṣẹ ọlọpaa lọ si kootu

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Kọmiṣanna feto idajọ nipinlẹ Ekiti, Amofin Wale Fapohunda, ti gbe ọga-agba ọlọpaa nilẹ…

Ọkunrin yii laye ti su oun, lo ba fẹẹ para ẹ n’Ikẹja, ọpẹlọpẹ LASEMA

Faith Adebọla, Eko Bi ko ba jẹ ti ajọ to n ri si iṣẹlẹ pajawiri nipinlẹ…

Dapọ Abiọdun kilọ fẹgbẹ awakọ ero ipinlẹ Ogun, o ni wọn ko gbọdọ de gareeji gbowo ita

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Ijọba Gomina Dapọ Abiọdun ti kilọ fẹgbẹ awakọ ero NURTW, nipinlẹ Ogun, lati…

Wahala awọn Fulani darandaran yii le da ogun abẹle silẹ ni Naijiria O-Ṣoyinka

 “Gbogbo wa o le sun ka kori sibi kan naa, ti gbogbo wa ba ni ka…

Ti Makinde ba gba mi laaye, Wakili, Fulani to dẹrujẹjẹ si wọn lọrun l’Ayetẹ, ko ni i lo ọjọ meji- Sunday Igboho

Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi ọmọ Fúlàní kan ti wọn n pe ni Iskilu Wakili ṣe…

Irọ ni wọn pa mọ mi o… Awujalẹ

 Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Lojiji niroyin kan gbode lọjọ Ẹti, Furaidee,  to kọja yii, pe Awujalẹ ilẹ Ijẹbu,…

Nitori wahala ọrọ ilẹ, ijọba kede konilegbele niluu Ilobu ati Ẹrin-Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kede konilegbele oniwakati mẹrinlelogun bayii latari wahala to n…

Ki ẹledaa awọn irunmọlẹ da a fun mi, to ba jẹ pe ohun ti mo lọọ ṣe l’Abuja yatọ si ọrọ ilẹ Yoruba-Ọọni

Jide Alabi Wahala buruku lo n ṣẹlẹ laarin awọn ọba alaye meji yii, Ọọni Ile Ifẹ,…

Mi o lọwọ si ikowojọ tawọn eeyan n ṣe nitori  mi- Sunday Igboho

Ọlawale Ajao, Ibadan Akọni ọmọ Yoruba nni, Oloye Sunday Adeyẹmọ,  ti gbogbo eeyan mọ sí Sunday…

Awakọ tirela gba oni-Maruwa lẹṣẹẹ, niyẹn ba ku patapata

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ẹka ti wọn ti n gbọ ẹsun ipaniyan ni ọkunrin kan bayii torukọ…

Awọn tọọgi ya bo ikọ Amọtẹkun at’ọlọpaa n’Ibadan, wọn ṣe mẹrin leṣe ninu wọn

Ọlawale Ajao, Ibadan Ba a ṣe n wi yii, ẹka ti wọn ti n tọju awọn…