L eyin wakati diẹ ti wọn kọ lu agọ ọlọpaa, awọn janduku tun dana sun ile rẹpẹtẹ n’Ibadan

Lẹyin wakati diẹ ti wọn kọ lu agọ ọlọpaa, ninu eyi ti eeyan meji ti dagbere…

Dẹrẹba ileewe pamari fipa ba ọkan ninu awọn akẹkọọ to n gbe lọ sileewe lo pọ l’Ogijo

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Fun pe o fipa ba ọmọbinrin ti ọjọ ori ẹ ko ju mẹrin…

Loootọ ni baba mi n ba mi lo pọ, ada ni wọn maa n yọ si mi ti wọn ba ti fẹẹ ṣe e-Fatimọa

Jide Alabi Gbogbo awọn to gbọ ni ko le gba eti wọn gbọ, iyẹn nigba ti…

Ọja ni mo n lọ ti ọta ibọn awọn ọlọpaa fi ba mi, diẹ lo ku ki n y’arọ – Khadija

Florence Babaṣọla Obinrin kan to fara han niwaju awọn igbimọ to n gbọ ẹsun awọn araalu…

Ọmọ Ilọrin ni mi o, Seriki Fulani Igangan pariwo

Dada Ajikanje Seriki Fulani niluu Igangan, nijọba ibilẹ Ibarapa, Alhaji Salihu Abdulkadir, ti sọ pe meje…

Awọn mẹrin to n fojubọ lu jibiti ti wọn tun n fọ ayederu owo n’Ijẹbu-Ode bọ sọwọ ọlọpaa

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ojubọ arumọjẹ kan wa lagbegbe Ijagun,nitosi Ijẹbu-Ode, nipinlẹ Ogun, inu igbo jingbun ni, awọn…

Tẹgbọn-taburo ti wọn n ṣe ‘Yahoo’ l’Oṣogbo ko sọwọ EFCC

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Akinrinmade Adepọju Sunday ati aburo rẹ, Akinrinmade Adeniyi, ni ọwọ awọn oṣiṣẹ ajọ…

Awakọ pa oṣiṣẹ LASTMA l’Ekoo

Jide Alabi L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii ni ẹṣọ agbofinro to n dari ọkọ, iyẹn LASTMA pade…

Tunde Bello ti wọn lo fipa ba obinrin sun lẹyin to ji i gbe ti wa l’Eleweeran

Aderounmu Kazeem L’Ọjọruu, Wẹsidee, ni olu ileeṣẹ ọlọpaa to wa ni Eleweran niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun,…

Awọn ileeṣẹ ibanisọrọ ti laṣẹ lati fun awọn eeyan ni nọmba idanimọ orileede (NIN) bayii

 Faith Adebọla  Ijọba apapọ ti fọwọ si i, wọn si ti fawọn ileeṣẹ ibanisọrọ laṣẹ lati…

Ṣoyinka tun kọ lu Buhari, o ni ijọba rẹ ko lokun lati gbogun ti iwa ibajẹ mọ

Faith Adebọla, Eko “Ti ki i baa ṣe pe o ti rẹ ijọba yii, ti wọn…