Ija n bọ: Awọn aṣofin ti ni kawọn olori ologun gbogbo fipo silẹ o

Ile-gbimọ aṣofin agba ilẹ yii ti paṣẹ loni-in yii pe ki awọn olori ologun gbogbo fi…

Awọn aṣofin beere boya o kowo jẹ ni o, n lọga ileeṣẹ NDDC ba daku

  Ọrọ buruku ni, koda o mu ẹrin lọwọ, ṣugbọn awọn ti wọn wa nibẹ ko…

Nitori owo itanran ti ko ri san, Fatai para ẹ sawọn TRACE lọrun l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọkunrin kan torukọ ẹ n jẹ Fatai Salami, pa ara ẹ si ileeṣẹ…

IBO APC: AKEREDOLU LO WỌLE

Ibo abẹle APC ti wọn di lanaa ni ipinlẹ Ondo, Gomina Rotimi Akeredolu lo ma wọle. …

ISSA FUNTUA, ỌKAN NINU AWỌN IGI-LẸYIN-ỌGBA BUHARI, TI KU O

NInu ile ijọba Aso Rock, a-gbọ-sọgba-nu ni iroyin iku ọhun jẹ. Awọn eeyan ibẹ ko tete…

Ibo abẹle Ondo: Kekemeke loun ko ni igbẹkẹle ninu ẹ, Abraham naa binu kuro

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Ọkan ninu awọn to n dije sipo gomina ninu eto idibo to n…

Ọwọ ijọba lo wa ti iwa ifipabanilopọ yoo ba dẹkun lorileede yii – Ẹlẹbuibọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Araba awo ti ilẹ Oṣogbo, Oloye Ifayẹni Ẹlẹbuibọn ti sọ pe ti iwa…

LONI-IN, AKEREDOLU YOO KOJU AWỌN ALATAKO Ẹ NINU APC L’ONDO

Boya Arakunrin Rotimi Akeredolu yoo tun ṣe gomina ipinlẹ Ondo lẹẹkan si i tabi ala ti…

Tẹgbọn-taburo dero ẹwọn, igbo ni wọn ka mọ wọn lọwọ n’Ileefẹ  

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ṣebi ọmọ-iya meji ki i ṣe owo aipe lawọn agbalagba maa n wi,…

Ẹ WOJU Ẹ: ẸNI TO PA TOLULỌPẸ AFẸRONPILEENI-JAGUN REE O

Ileeṣẹ ologun ofurufu ilẹ wa ti kede, lọṣan-an yii, oruko ẹni to pa Tolulọpẹ Arotile, ọmọbinrin…

Ileeṣẹ agunbanirọ fiya jẹ mọkanla ninu wọn to n sa lẹnu iṣẹ

 Ọlawale Ajao, Ibadan  Yatọ si awọn meji to j’Ọlọrun nipe lasiko ti wọn n ṣiṣẹ sin…