Awọn Fulani yii tun ji baba agbẹ gbe n’Igboọra

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọwọ awọn agbofinro tun ti tẹ awọn Fulani mi-in ti wọn ji ọkunrin…

Ijọba Buhari yii lo n sọ awọn ọmọ Naijiria dọta ara wọn, Ọbasanjọ lo sọ bẹẹ

“Lọjọ ti mo ti gbọnju, emi o ri igba kankan ni orilẹ-ede wa yii ti awọn …

Ija rẹpẹtẹ nile awọn MKO Abiọla, awọn ọmọ gba kootu lọ

Ija kan n fẹju bọ nile Oloogbe Moshood Kaṣimawo Abiọla bayii o. Ija naa ti le…

Ẹ wo Matthew, ọmọ ileewe ẹ lo fipa ba lo pọ ni Sango

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Tiṣa lọkunrin tẹ ẹ n wo yii nileewe aladaani kan ti wọn forukọ…

Ẹrọ idibo to le ni ẹgbẹrun marun-un lo bajẹ nibi ina to jo l’Ondo- INEC

Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ Kọmiṣanna to wa fun eto iroyin ati ilanilọyẹ nipa idibo ti ajọ eleto…

Bi Ọlọrun ṣe yọ ọgọrin eeyan n’Ijọra Badia ree o, diẹ lo ku ki ile wo pa wọn

Aderounmu Kazeem Eeyan bi ọgọrin atawọn ọmọde bii aadọta lori ko yọ lasiko ti ile alaja kan da wo lulẹ ni…

Sadia kọ ọkọ ẹ silẹ n’Ibadan, o lo ji pata oun mu

Ọlawale Ajao, Ibadan Pátá lásánlàsàn lo da igbeyawo ọdun mẹta ru n’Ibadan pẹlu bi ile-ẹjọ ṣe…

Tẹgbọn-taburo n ṣe yahoo n’Ibadan, wọn ti mu wọn o

Pako bayii lawọn ọmọ iya meji kan, Ayọọla Timilẹhin, Oluṣọla Timilẹhin atawọn ọre wọn n wo…

Nitori Ọọni Ile-Ifẹ, Fani Kayọde sọko ọrọ si Tinubu

Minisita to n ri si igbokegbodo ọkọ ofurufu nilẹ wa tẹlẹ to tun jẹ ọmọ bibi…

Wahala n bọ o, Makinde ati Fayoṣe fẹẹ gbena woju ara wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Ogun Bi awọn agbaagba ẹgbẹ oṣelu PDP ko ba tete wa nnkan ṣe si…

Ọmọ iya meji ti rewele o, Taiwo ati Kẹhinde to lu oyinbo ni jibiti ko sọwọ EFCC n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Awọn ọmọ iya meji kan ti rewele bayii o pẹlu bi ọwọ Ajọ…