Ina jo Ọja Tuntun niluu Ile-Ifẹ

Idowu Akinrẹmi, Ikire Inu Ibanujẹ nla lawọn oniṣowo ninu Ọja Tuntun to wa niluu Ile-Ifẹ, wa…

Toromagbe, baba Oriṣabunmi ninu sinima Arelu, ti ku o

Aderounmu Kazeem Ọgbọnjọ oṣu kọkanla ọdun yii ni wọn sọ pe Oloye Abdul Tawab Ọlaitan Ile-Aje…

Ọwọ ti tẹ awọn janduku to ṣeku pa Ọba Olufọn l’Ondo

Aderounmu Kazeem Ni bayii, ọwọ ti tẹ awọn janduku kan ti wọn sọ pe o ṣee…

Lẹyin ọdun mẹẹẹdogun: Ọbasanjọ ati Gani Adams pari ija, nitori iṣọkan ilẹ Yoruba

Aderounmu Kazeem Lẹyin ọdun mẹẹdogun, ija to wa laarin Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ ati Aarẹ Gani Adams…

Fani-Kayọde ko yọju si kootu, lawọn EFCC ba n bẹbẹ pe ki wọn jẹ kawọn gbe e

Aderounmu Kazeem Ile-ẹjọ giga kan niluu Abuja ti kọ lati fun ajọ EFCC laṣẹ lati lọọ…

Ofofo wa ti wọn ṣe la fi ṣeku pa awọn agbẹ bii ọgọrin ni Borno – Boko Haram

Jide Alabi Ẹgbẹ afẹmiṣofo nni, Boko Haram, ti sọ pe awọn gan-an lawọn ṣeku pa awọn…

Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori ọmọ marun-un to sọnu nile awọn alainiyaa Stella Ọbasanjọ 

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Titi dasiko ta a pari iroyin yii ni wọn ṣi n wa awọn…

Arun korona tun paayan mẹta l’Ekoo, ọtalelelọgọfa ti tun lugbadi ẹ

Faith Adebọla, Eko Afaimọ ko ma jẹ pe arun aṣekupani buruku nni, koronafairọọsi, tun ti fẹẹ…

Emir Kano wọlu Ẹgba, o ṣabẹwo si Gomina Dapọ Abiọdun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun, gba alejo ọba ipinlẹ Kano, Emir Aminu…

Ija pari! Ebenezer Obey pari ija Wasiu Ayinde ati awọn ẹbi Barrister

Ija ati awuyewuye to n waye laarin olorin fuji nla nni, Alaaji Wasiu Ayinde Marshal, ẹni…

Ọwọ tẹ mẹwaa ninu awọn to n fọ ọpa epo bẹntiroolu ati ọkọ ti wọn n lo l’Arepo

Ọpẹlọpẹ awọn araalu ti wọn fura, ti wọn si tete ta awọn agbofinro lolobo loru ọjọ…