Faith Adebọla, Eko Ile-igbimọ aṣofin Eko ti fi aidunnu wọn han si bi wahala awọn janduku…
Author: Alaroye
Olori ileegbimọ aṣofin agba ni ki Buhari yọ awọn ọga ologun nipo
Olori ile-igbimọ aṣofin agba, Ahmed Lawan, ti ke si Aarẹ Muhammadu Buhari lati yọ awọn olori ẹṣọ…
‘Nitori korona, ẹ yẹra fun ikorajọ ati orin aisun alẹ Keresi lọdun yii o’
Faith Adebọla, Eko Ijọba apapọ ti gba awọn ẹlẹsin Kristẹni nimọran pe tori arun korona, ki…
Awọn Aṣofin agba ti fọwọ si i ki Mahmud Yakub maa ṣe alaga INEC lọ
Ile-igbimọ aṣofin agba ti fọwọ si i bayii pe ki Ọjọgbọn Mahmud Yakub to jẹ alaga…
Taoreed Farounbi, Baba Alado, wọ wahala, wọn ni afẹmiṣofo ni
Olori ọja Aswani, l’Ekoo, Oloye Toareed Farounbi, ẹni tawọn eeyan tun mọ si Baba Alado, atawọn…
Orileede Nijee lọwọ ti tẹ Maina, ọkunrin to ko owo awọn oṣiṣẹ-fẹyinti je
Irọlẹ ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni ọwọ awọn ọlọpaa ọtelẹmuyẹileeṣẹ EFCC pẹlu ifọwọsowọpọ awọn ọtelẹmuyẹ…
Oṣiṣẹ kootu jale, ni wọn ba wọ wọn lọ sile-ẹjọ l’Oṣogbo
Florence Babasola, Oṣogbo Igi a fẹyinti, to jẹ gbogbo ara kiki ẹgun lọrọ awọn oṣiṣẹ ile-ẹjọ…
Latọdun to n bọ lọ, gbogbo ẹni to ba fẹẹ gba nọmba ati lansẹnsi gbọdọ ni kaadi idanimọ ilẹ wa –FRSC
Ọga agba ajọ ẹṣọ oju popo nilẹ wa, (FRSC), Ọgbẹni Boboye Oyeyẹmi, ti kede pe bẹrẹ…
Makinde ṣabẹwo si Oyetọla, o ni oun mọriri ipa to ko lori ọrọ LAUTECH
Florence Babaṣọla Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ṣeyi Makinde, ti ṣabẹwo si ojugba rẹ ni ipinlẹ Ọṣun, Alhaji…
Awọn ogoji agbẹ ti Boko Haram pa ko gba aṣẹ ki wọn too lọ sinu oko wọn – Ọmọọṣẹ Buhari
Aderounmu Kazeem Pupọ ninu awọn ọmọ orilẹ-ede yii ni inu wọn ko dun rara lori ọrọ…
Nitori awọn agbẹ onirẹsi mẹtalelogoji tawọn Boko Haram bẹ lori ni Borno, PDP sọko ọrọ si Buhari
Ẹgbẹ oṣelu PDP ti sọ pe ohun to foju han bayii ni pe eto aabo ti…