Nitori ẹsun idigunjale, adajọ ni ki wọn yẹgi fun Adekunle ati Chinedu l’Ado-Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Onidaajọ Adekunle Adelẹyẹ tile-ẹjọ giga ilu Ado-Ekiti ti dajọ iku fawọn meji kan,…

Tadenikawo, Adesọji, Aderẹmi lorukọ ọmọ Ọọni tuntun

Dada Ajikanje Lẹyin ọpọlọpọ etutu gẹgẹ bii iṣẹdalẹ Yoruba, wọn ti sọ arole Ọọni Ileefẹ, Ọba…

Maradona, ogbontarigi agbabọọlu ilẹ Argentina, ti ku o!

Faith Adebọla, Eko Gbogbo awọn ololufẹ ere bọọlu ni wọn ti n daro ogbontarigi agbabọọlu ọmọ…

Ẹ wo awọn adigunjale mẹrin tọwọ tẹ l’Alakukọ

Faith Adebọla, Eko  Ahamọ ọlọpaa lawọn afurasi ọdaran mẹrin kan, Micheal Mustapha, ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn, Suleiman…

O ma ṣe o, akẹkọọ UNIOSUN para ẹ, majele lo gbe jẹ

Florence Babasola, Oṣogbo Akẹkọọ kan to wa nipele akọkọ ni ẹka ileewe UNIOSUN to wa niluu…

Wọn la maneja banki mẹwọn l’Ekoo, ọgọsan-an miliọnu naira lo poora mọ ọn lọwọ

Faith Adebọla, Eko Ọgba ẹwọn to wa l’Alagbọn, Ikoyi, nipinlẹ Eko, nile-ẹjọ giga tijọba apapọ kan…

Ipo Aarẹ 2023: Faṣhọla rọ ẹgbẹ oṣelu APC lati tẹle adehun

Amofin agba Babatunde Faṣhọla, ti da sọrọ to n ja ran-in-ran-in nilẹ lori apa ibi ti…

Tori temi ni Akeredoku ṣe yọ kọmisanna eto idajọ ati igbakeji olori awọn aṣofin- Ajayi

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbakeji Gomina Ipinlẹ Ondo, Ọnarebu Agboọla Ajayi ti bu ẹnu atẹ lu yiyọ…

Ori eeyan mẹrin, ọwọ meji, ni Salisu lọọ hu nitẹ-oku n’Ijẹbu-Ode

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Ẹru ofin gbaa ti wọn ko gbọdọ ba lọwọ ọmọluabi lawọn ọlọpaa ipinlẹ…

Eeyan meji ku nibi ija ọlọkada atawọn alakooso ọgba ẹwọn n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Eeyan meji ni wọn lo riku ojiji he lasiko ti awọn ọlọkada atawọn…

Awọn aṣofin Ondo yọ igbakeji abẹnugan nipo, wọn fi Aderọboye rọpo rẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Ondo ti yọ Ọnọrebu Irọju Ogundeji gẹgẹ bii igbakeji abẹnugan.…