Ile-ẹjọ to ga ju lọ nilẹ wa da Adeleke lare

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ile-ẹjọ to ga ju lọ lorileede yii ti dajọ pe Senetọ Ademọla Adeleke…

Tinubu ko si nibi ipade alaafia ti awọn oludije funpo aarẹ ṣe l’Abuja  

Jọkẹ Amọri Gbogbo eeyan lo n garun lọtun-un losi, ti wọn si n wo raaraara, nigba…

Ina jo ilegbee awọn akẹkọọ Kwara Poli, ọpọ dukia lo segbe

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kejidinlọgbọn, oṣu Kẹsan-an yii, ni ina deede ṣẹ yọ ni…

Olori ilegbimọ aṣofin agba, Lawan, ti ja bọ o

Faith Adebọla Ile-ẹjọ giga apapọ kan to fikalẹ siluu Damaturu, nipinlẹ Yobe, ti gbegi dina fun…

Ile ọti ni awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun yinbọn pa Tajudeen si n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ni nnkan bii aago mẹwaa alẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kẹtadinlọgbọn, oṣu Kẹsan-an,…

Ọwọ tẹ awọn ọrẹ mẹta to n ja ero inu ọkọ lole ni Koṣọfẹ

Jọkẹ Amọri Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ni tolohun, bẹẹ gẹlẹ lọrọ ri fawọn ọrẹ…

Ẹ gbadura fun Baba Ijẹṣa o, ara rẹ ko ya  ko ya gidigidi lẹwọn o

Faith Adebọla Afi ki gbogbo mọlẹbi atawọn ololufẹ gbajugbaja adẹrin-in poṣonu ilẹ wa nni, James Ọlanrewaju…

Wọti mu an ninu awọn Fulani to n jiiyan gbe ni Kaara

Gbenga Amos, Ogun Adura ‘arinna-kore, akoya-ibi’ lawọn ero meje to wọkọ ayọkẹlẹ Ford kan gba, nigba…

Mo n wa obinrin to le ba mi gbe oyun, emi naa fẹẹ bimọ ti yoo jogun mi – Bobrisky

Monisọla Saka Ọmọkunrin kan to sọ ara rẹ di obinrin nipa mimura bii abo, to tun…

Oriṣa yoowu to ba fẹẹ kọ lu mi yoo jiyan rẹ niṣu-Oluwoo

Theo Ọmọlohun, Oke-Ogun Oluwo ilu Iwo, Ọba Abdulwaheed Adewale Akanbi, Tẹlu kin-in-ni, ti ṣekilọ fawọn oriṣa…

Gbese ti mo jẹ ni mo n wa owo rẹ ti mo fi tẹle wọn lọọ jiiyan gbe-Adewale

Ọlawale Ajao, Ibadan Marun-un lawọn afurasi ajinigbe ọhun, Abọlaji Azeez Aleṣe Bakare (BJ), ọmọ bibi Agọ-Iwoye, ni ipinlẹ…