O maa se o! Agbara ojo wọ eeyan meje lọ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan, eeyan meje lo ti padanu ẹmi wọn, ti ọpọ dukia…

Baba atọmọ pa Gbenga, wọn kun ẹya ara ẹ si wẹwẹ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lori ẹsun siṣeku pa Gbenga Abiọla, ti wọn si tun ko ẹya ara…

Alaga ijọba ibilẹ Ido lu lọọya lalubami n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin oṣu kan aabọ ti wọn da alaga kansu Ido, nipinlẹ Ọyọ, Ọnarebu Sherif…

Eedi ree o, Daniel gun ọrẹ ẹ pa nitori ounjẹ

Monisọla Saka Ọmọdekunrin kan, Daniel Akindele, ti dero atimọle bayii lẹyin ti wọn fẹsun kan an…

Inu lailọọnu ounjẹ ọmọde lawọn eleyii rọ igbo si

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ to n gbogun ti oogun oloro nilẹ yii, NDLEA, ti tẹ awọn…

Pasitọ Fẹmi ati Aafaa Kabiru ni mo maa n ta ẹya ara oku ti mo ba hu fun-Ismaila

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ismail Adewuyi, ọmọ ọdun mejidinlọgbọn, to ge ori nitẹẹku awọn Musulumi ti wa…

”Yẹyẹ ti wọn n fi mi ṣe nitori mi o rọmọ bi lo jẹ ki n lọọ j’ọmọ gbe lọsibitu”

Faith Adebọla Ẹdun ọkan ati omije iya ibeji kan, Bilkisu Alhassan, ti pada di ayọ, nigba…

Awa ọba lo yẹ ki ijọba apapọ fi iṣakoso eto aabo le lọwọ-Oluwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lati le wa ojutuu si wahala aisi eto aabo to peye lorileede Naijiria,…

Ọyọmesi din orukọ awọn to n dupo Alaafin ku si mẹwaa

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọyọmesi, iyẹn awọn afọbajẹ ilu Ọyọ ti din orukọ awọn to n dupo…

Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun yinbọn pa akẹkọọ Yabatech

Monisọla Saka Niṣe lawọn akẹkọọ ile ẹkọ giga Yabatech, n sa asala fun ẹmi wọn ninu…

O ṣee ṣe ki ẹgbẹ PDP padanu ibo aarẹ ọdun to n bọ – Bọde George

Monisọla Saka Eekan ninu ẹgbẹ oṣelu PDP, Oloye Bọde George, ti ni dugbẹdugbẹ to n fi…