Awọn Fulani to sa kuro n’Igangan ya wọ Igbẹti, lawọn araalu ba dawo ọkọ fun wọn pe ki wọn maa lọ

Olu Theo Ọmọlohun, Oke-Ogun

Ko din laaadrin (70) awn Fulani darandaran ti wsa kuro n’Igangannijba ibil Ila-Oorun Ibarapa, lyin iklu ti we sawn araalu naa ti wọn tun sa wọ Igbẹti, nipinlẹ Ọyọ lọjọ Ẹti to kọja yii ti i ṣe ọjọ kọkanla, oṣu kẹfa. Ṣugbọn awọn araalu naa ko gba wọn laaye, niṣe ni wọn dawo ọkọ fun wọn pe ki wọn maa lọ.

 Ggẹ ba a e gb, awn Fulani naa ti pup ninu wn j obinrin, ati mọ-ọw wọn ni wọn de si Igbẹti plu dukia wn. k akero meji ni wọn gbe wọ ilu naa lati Igangan, ṣugbn ilu Ilero ni il u wn si.

Nigba ti wọn ta Elero tilu Ilero, ba Wasiu Saka Olokolonigi, lolobo nipa awn alejo naa, Kabiyesi yari pe ko saaye fawọn eeyan naa niluounTean lpaa ilu naa ni wn sun mju j keji, ko too di pe wn tk leti gba na ilu Igboho lọ. Ṣugbọn niṣe ni wọn tun le wọn n’Igboho naa.

Lẹyin naa ni wọn kọri si ọna Igbẹti, bi wọn ṣe debẹ tawn araalu ri wn lawnaa ke si Onigbti, ba Emmanuel Oyekan Oyebisi, loun naa ba pe Eria Kmanda agbegbe naa, AC Taiwo Adedeji, ni to fidi iṣẹlẹ naa mulẹ, pe awn araalu lo pada sanwo k tawFulani naa wọ lati ilu Ilero, nigba tawn drba k to gbe wn wa yari pe owo k Igbti ni wn san fawn.

Alaga m Igbti, Oloye Fashina Alawọde, naa fidi iṣẹlẹ yii mulẹ. O ni awm ilu naa ni wn da gbrun mtala naira fawn Fulani naa pe ki wn maa ba tiwn l.

lawn gbe igbes yii lati koore Eṣu ni, kohun to ṣẹlẹ nIgangan ma baa tun ṣẹlẹ.

 Adugbo Oko Olowo, loju ọna to lọ si Jẹbba, ni wọn pada fi mọto ko awọn Fulani naa lọ.

Ọkan ninu awọn dẹrẹba to wa wọn lọ, Ọgbni Moṣọp Matthew, sọ pe plu iranlw awagbofinro bii Sifu Difnsi ati Amtkun ni wn fi siwn de adugbo Oko Olowo, loju na maros to l siluu Jbba. Ibẹ ni wọn ja wọn si pe ki wọn maa ba tiwọn lọ

Leave a Reply