Awọn ọdọ to n fehonu han ti ya de ile Tinubu ni Bourdilon, n’Ikoyi

Kazeem Aderohunmu

O jọ pe ọrọ yii ti kọja ohun tawọn eeyan ro pe yoo kan lọolẹ bẹẹ, nitori niṣe lo n le si i.

Nile Bọla Tinubu, n’Ikoyi, lawọn ọdọ to n ṣewọde kiri yii tun ti wa bayii, o si jọ pe ọrọ ọhun ko ni i rerin-in ti wọn ba ṣe ohun ti wọn ti n ṣe kaakiri gbogbo ibi ti wọn ti lọ nile ẹ ti wọn wa bayii.

Ba a ti ṣe n ko iroyin yii jọ, orin buruku, orin ọtẹ ni wọn n kọ, bẹẹ lọrọ wọn ti di eṣin ko kọ iku.

About Alaroye

Journalist, Press man and News Researcher of the federal Republic of Nigeria

Check Also

Nitori obinrin, Danladi gun ọrẹ rẹ pa l’Ode-Aye

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin ẹni ọdun mejilelogun kan, Money Danladi, ni wọn ti fẹsun kan …

One comment

  1. Ibeere temi nope kini anfi ibon se gan ni ilu yi,?has!! Owo nla nla ti won fi nra ibon ati ota ibon tan Awon isoro ti aba nike yii
    Debipe ibon ni amama fise atori lati ba omo ilu wii oguna orilede e bomi PA won
    ORO NLA Leda !!!¡

Leave a Reply

//ugroocuw.net/4/4998019
%d bloggers like this: