Awọn ọmọọta dana sun agọ ọlọpaa Apapa-Iganmu

Aderohunmu Kazeem

Ni nnkan bii aago mẹsan-an aarọ yii ni awọn ọmọọta kọ lu agọ ọlọpaa to wa ni Orile Iganmu, ti wọn si dana sun un.

Awọn ọmọọta to ṣiṣẹ ibi naa ko fu awọn ọlọpaa to wa ni teṣan ọhun lara rara ti wọn fi sọna si i, ti ina naa si n jo ni koṣẹ koṣẹ. Wọn ti ranṣẹ pe awọn panapana lati waa dẹkun ina naa.

One thought on “Awọn ọmọọta dana sun agọ ọlọpaa Apapa-Iganmu

  1. eero temi nipe awon janduku ti won se iwode yi ohun ti won se dara toba je pe won se ni wooro ni sugban ile ti won danasun yi gan ni kodara ohun ti emi lero ni pe awon janduku ti awon olopa yi ti se tele boya won ti fiya ai nidi je wori ni won lo anfani iwode yi gbesan ki olorun bawa petu si won ninu

Leave a Reply