Buhari tun yan alaga ajọ eleto idibo, Mahmood, fun ọdun marun-un mi-in

Aarẹ Muhammadu Buhari ti tun yan alaga ajọ eleto idibo ilẹ wa, Mahmood Yakubu, pada si ipo alaga ajọ naa.

Pẹlu anfaani tuntun yii, ọkunrin naa ni yoo tun ṣeto idibo ọdun 2023.

Leave a Reply