Akíntọ́lá

Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba ti ẹgbẹ Dẹmọ kọwe pe ki wọn ma ti i fi Awolọwọ silẹ lọgba ẹwọn

Nigba ti awọn eeyan bẹrẹ si i pariwo lẹyin ti wọn ti dibo ọdun 1964 tan pe ki wọn fi Oloye Ọbafẹmi Awolọwọ to wa lẹwọn silẹ ko maa lọ sile ni alaafia, inu awọn kan n dun, ṣugbọn dajudaju, inu ẹgbẹ Dẹmọ, bẹrẹ lati ọdọ olori ẹgbẹ naa ti i ṣe Oloye Ladoke Akintọla ati awọn aṣaaju ẹgbẹ wọn gbogbo ko dun rara …

Read More »
//lephaush.net/4/4998019