Awọn eeyan ba agbabọọlu ilẹ wa, Ahmed Musa, yọ fun ọmọkunrin lantilanti lo bi

Oluyinka Soyemi Ikinni ‘ẹ-ku-oriire’ lawọn eeyan n ki atamatasẹ ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles to n ṣe…

Esi awọn ifẹsẹwọnsẹ to pari Premier League ilẹ England fun saa 2019/20

Oluyinka Soyemi Lonii ni awọn ifẹsẹwọnsẹ to gbẹyin saa 2019/20 ninu idije Premier League ilẹ England waye.…

Man City din dundu iya fun Watford

Oluyinka Soyemi Dundu iya ami-ayo mẹrin si odo ni Manchester United din fun Watford lalẹ yii…

Awọn ololufẹ Samuel Kalu to ko Korona wọle adura fun un

Oluyinka Soyemi Awọn ololufẹ agbabọọlu ilẹ Naijiria to n ṣe bẹbẹ ni Bordeaux, ilẹ France, Samuel…

FA Cup: Arsenal ati Chelsea yoo koju ara wọn fun aṣekagba

Oluyinka Soyemi Ẹgbẹ agbabọọlu Arsenal ati Chelsea yoo pade nibi aṣekagba idije FA Cup lọjọ kin-in-ni,…

Nilẹ Zambia, eeyan mejidinlọgbọn ko Koronafairọọsi ni kilọọbu kan

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ṣe lawọn alaṣẹ liigi ilẹ Zambia to yẹ ko bẹrẹ lọjọ Abamẹta, Satide,…

Dessers darapọ mọ Genk ilẹ Belgium

Oluyinka Soyemi Atamatase ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles tuntun, Cyriel Dessers, ti darapọ mọ Kilọọbu Genk ilẹ…

Nwakali gba bọọlu fun kilọọbu lẹyin ọdun kan

Oluyinka Soyemi Lẹyin ọdun kan ati oṣu mẹta ti balogun ikọ agbabọọlu Golden Eaglets ilẹ Naijiria…

Joshua ati Fury ti ṣetan lati ja nigba meji – Eddie Hearn

Oluyinka Soyemi Gbajugbaja eleto ẹṣẹ kikan, Eddie Hearn, ti kede pe Anthony Joshua ati Tyson Fury…

Miliọnu mẹwaa Yuro ni Partizan fẹẹ ta Umar Sadiq

Oluyinka Soyemi Ẹgbẹ agbabọọlu Partizan Belgade, ilẹ Serbia, ti sọ pe miliọnu mẹwa Yuro lawọn fẹẹ…