Eyi lawọn ti ẹgbẹ APC fọwọ si pe wọn kunju oṣuwọn lati dupo gomina l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbimọ ti ẹgbẹ All Progressive Congress lorilẹ-ede yii gbe kalẹ lati ṣe ayẹwo…

Oluwoo we lawani fun Imaamu Agba tuntun niluu Iwo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti we lawani fun Muhammed…

O ṣẹlẹ, eyi nidi ti igbẹjọ Bobrisky ko fi waye

Monisọla Saka Gbajumọ ọkunrin bii obinrin nni, Idris Ọlanrewaju Okunẹyẹ, tawọn eeyan mọ si Bobrisky tabi…

Eleyii gbẹnu tan! Alaaji Mashood ki ọmọ bibi inu ẹ mọlẹ, o ṣe ‘kinni’ fun un ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Baale ile kan, Alaaji Mashood, to n gbe ni agbegbe Ọlọrunṣogo, Bodè-Sáadú, nijọba…

Ile-ẹjọ ni ki alaga PDP Ekiti ti wọn feṣun idaluru kan maa lọ layọ ati alaafia

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ Majisreeti kan ni Ado-Ekiti, nipinlẹ Ekiti, ti paṣẹ itusilẹ alaga ẹgbẹ PDP…

Lai fakoko ṣofo, Obaseki yan Godwin rọpo igbakeji rẹ ti wọn yọ nipo

Faith Adebọla Lẹyin wakati diẹ ti wọn kede iyọnipo Ọgbẹni Philip Shuaibu, ti i ṣe igbakeji…

Oṣere tiata yii ju bọmbu ọrọ: Mo le gba ọmọ ale tiyawo mi gbe wa lati ita

Monisọla Saka Ọkan lara awọn oṣerekunrin ilẹ wa to tun jẹ gbajumọ adẹrin-in-poṣonu, Babatunde Bernard Tayọ,…

Mo kabaamọ pe mo gun iyawo mi pa nitori ọrọ foonu-Abubakar

Monisọla Saka Ọwọ awọn agbofinro ipinlẹ Adamawa, ti tẹ Ibrahim Abubakar, ẹni ọdun mẹtalelọgbọn (33), nitori…

Idigunjale lawọn eleyii fi n ṣe ankoo, kẹkẹ Marwa ni wọn maa n ja gba

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa agbegbe Jimeta-Mubi, nipinlẹ Adamawa, ni awọn adigunjale ikọ ẹlẹni mẹrin kan ti wọn ti jingiri ninu…

Araalu meji padanu ẹmi wọn nibi ija agba awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun

Adewale Adeoye Ṣe lọrọ di bo o lọ o yago lasiko tawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun meji kan doju ija kọra wọn…

O ṣẹlẹ, eyi nidi ti igbẹjọ Bobrisky ko fi waye mọ

Monisọla Saka Gbajumọ ọkunrin bii obinrin nni, Idris Ọlanrewaju Okunẹyẹ, tawọn eeyan mọ si Bobrisky tabi…