Ẹgbẹ oniṣẹṣe kilọ fawọn ọdọ: Itanjẹ lasan ni, ko si nnkan to n jẹ oogun-owo ninu Ifa

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Pẹlu bi ọpọ awọn ọdọ orileede yii ṣe n fi ẹmi ara wọn…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Fathia Balogun

Monisọla Saka Asiko yii ki i ṣe eyi to dara rara fun ọkan ni awọn gbajumọ…

Ẹwọn n run nimu ọkunrin to n ṣe piọ wọta yii o, inu kanga lo ti n pọn’mi to n rọ sinu ọra

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti tẹ ọkunrin ẹni aadọta ọdun kan, Ọgbẹni…

A maa bẹrẹ si i ṣe ayẹwo ọpọlọ fawọn arufin oju popo ka a too pe wọn lẹjọ – Ijọba Eko

Monisọla Saka Ijọba ipinlẹ Eko ti ni gbogbo arufin ojupopo ti ọwọ ba ti tẹ lati…

Ijọba Kwara ti bo awọn ẹran maaluu to jẹ majele tawọn alapata kan fẹẹ maa ta faraalu mọlẹ 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Wọn ni ohun ti a o ba fẹ ko bajẹ, oju ni a…

Tinubu tun fẹẹ yawo lọwọ Banki Agbaye

Faith Adebọla Minisita fun eto iṣuna-owo nilẹ wa, Ọgbẹni Wale Ẹdun, ni gbogbo eto ti pari,…

Aarẹ Tinubu n lọ s’orileede Netherlands, yoo gba’bẹ sọda si Saudi

Faith Adebọla Bi ilẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kẹtalelogun, oṣu Kẹrin, ọdun 2024 yii ṣe n…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun ti Bobrisky ṣẹ ninu ọgba ẹwọn to wa

Faith Adebọla Ọrọ kan to n ja ranyin lori ẹrọ ayelujara bayii ni bi gbajugbaja ọkunrin…

Tirela kọ lu kẹkẹ Maruwa ni Sango-Ọta, ẹni kan ku lẹsẹkẹsẹ, ọpọ ṣeṣe

Faith Adebọla Ọkọ akẹru gbọgbọrọ kan ti ko mọlẹbi baale ile kan to doloogbe sinu ọfọ…

Wọn lawọn alapata kan n ta ẹran maaluu ti majele pa faraalu n’Ilọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣe ni ibẹrubojo gbilẹ niluu Ilọrin ati gbogbo agbegbe rẹ lati ọjọ Aiku,…

Eedi ree, baba atọmọ ku sinu ṣalanga nibi ti wọn ti fẹẹ yọ foonu

Adewale Adeoye Baba agbalagba kan, Oloogbe Mallam Danjuma, ẹni ọgọta ọdun tawọn eeyan mọ si Black…