Wọn mu akanda ẹda to n ṣowo egboogi oloro l’Ekoo

Wọn mu akanda ẹda to n ṣowo egboogi oloro l’Ekoo Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa agbegbe Akinpẹlu, niluu Oshodi, ipinlẹ Eko, ni akanda ẹda…

Eyi le o! Awọn ẹlẹwọn jẹ majele mọ ounjẹ, awọn mẹfa ti wa nileewosan

Adewale Adeoye Mẹfa lara awọn ẹlẹwọn kan ti wọn jẹ majele mọ’nu ounjẹ ti wọn jẹ lorileede Gẹẹsi ni wọn ti sare…

Mọto to n ko awọn to n lọọ ṣọdun Ajinde nijamba, eeyan marundinlaaadọta lo ku

Adewale Adeoye Ina lo jo awọn arina-ajo kan ti wọn n lọọ ṣọdun Ajinde gburugburu niluu Limpopo, lorileede South Africa.…

Iya ọna meji: Lẹyin ti wọn ja baale ile kan lole tan, awọn adigunjale tun fipa ba iyawo rẹ sun niṣoju ẹ

Adewale Adeoye Mẹta lara awọn adigunjale kan ti wọn lọọ ja Ọgbẹni Mudan Ibrahim, to n gbe lagbegbe Chori, nijọba ibilẹ Ringim, nipinlẹ Jigawa,…

Eyi ni ohun ti Adeleke sọ nipa Tinubu

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke, ti ṣapejuwe Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, gẹgẹ…

Awọn ọlọpaa le adigunjale mẹrin bii ehoro ni Sango, ọwọ ba meji ninu wọn

Faith Adebọla Ọwọ palaba meji ninu ikọ adigunjale ẹlẹni mẹrin kan ti segi nipinlẹ Ogun, niṣe…

Oluwoo ṣedaro Imaamu agba ilu Iwo to doloogbe

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Wọn ti kede iku Imaamu Agba ilu Iwo,  Sheik AbdulFatahi Olododo, ẹni to…

N’llọrin, Haruna ti n lọ si ọgba ẹwọn ba a ṣe kọwe rẹ, jibiti to lu lo n gbe e lọ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ giga kan niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ti sọ ọkunrin kan to maa…

Niṣe lawọn eleyii maa ṣe bii ero ọkọ, foonu awọn ero ni wọn maa n dọgbọn ja gba

Adewale Adeoye Awọn agba bọ wọn ni ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ni t’olohun, bẹẹ gẹlẹ lọrọ ri fawọn ole ẹlẹni…

Iru ki waa leleyii! Baale ile yii lu iyawo rẹ pa nitori ọrọ ti ko to nnkan

Adewale Adeoye Ko jọ pe Ọgbẹni Emmanuel Okpara yoo bọ ninu wahala to ko ara rẹ si…

O ṣẹlẹ, tọọgi kọ lu awọn afọbajẹ l’Ararọmi-Ekiti  

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti  Ọrọ a o jọba, a ko jọba ti mu wahala nla dani, to…