NAFDAC ti awọn ileeṣẹ burẹẹdi ati ti piọ-wọta ti ko niwee ijọba  pa

Adewale Adeoye Ajọ to n ri sohun jijẹ ati mimu lorileede wa, NAFDAC, ẹka ipinlẹ Rivers, ti ti awọn…

Ẹwọn gbere ni adajo ju baale ile to fipa b’ọmọ ọdun marun-un sun l’Ekoo si

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Rahman Oṣhodi, tile-ejọ kan to n ri si ẹsun fifipa ba ọmọde sun ati lilo ọmọde nilokulo niluu Eko, ni wọ…

Adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun oyinbo Chinese to pa ọrẹbinrin rẹ ni Kano

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Sanusi Ado Ma’ aji, tileejọ giga kan to wa lagbegbe Bompai, nipinlẹ Kano, ni wọn foju oyinbo Chinese kan, Ọgbẹni…

Ọran nla! Awọn agbebọn ji Imaamu agba gbe ni Kogi

Adewale Adeoye Bẹẹ ba n ri awọn ọlọpaa atawọn agbofinro gbogbo niluu Iyara, nijọba ibilẹ Ijumu, nipinlẹ Kogi, ti wọn n wọnu igbo…

 Ọwọ ẹṣọ Amọtẹkun tẹ awọn afurasi ole meje l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kẹrindinlọgbọn oṣu Kẹta, ọdun 2024 yii, lawọn ẹsọ Amọtẹkun…

Ile ti Gbenga lọọ ba wọn kun lo ti ji aṣọ ẹgbẹrun lọma ọgọrun-un Naira l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọkunrin ẹni ọdun mọkanlelọgbọn kan to n ṣe iṣẹ kunle- kunle (painter) Ọgbẹni…

Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori obinrin ti wọn ge ori rẹ lọ l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti bẹrẹ iwadii lori ọrọ obinrin kan ti wọn…

Ọta ilọsiwaju lawọn ti wọn maa n ba dukia ijọba jẹ lasiko rogbodiyan – Arẹgbẹṣọla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Minisita tẹlẹ fun ọrọ abẹle lorileede yii, Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, ti sọ pe…

Ija buruku laarin Portable ati Bobrisky, eyi lohun to fa a

Monisọla Saka Ko ti i sẹni to mọ ẹni ti yoo pari ija buruku to n…

Amọtẹkun le oṣiṣẹ wọn mẹta danu l‘Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn oṣiṣẹ ẹsọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo mẹta ni iṣẹ ti bọ lọwọ wọn…

Nitori ẹsun wiwa kusa lọna aitọ, afurasi marun-un ha ṣakolo EFCC n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ajọ to n gbogun ti iwa jibiti ati ṣiṣe owo ilu mọkumọku…