Adewumi Adegoke Igbakeji aarẹ ilẹ wa tẹlẹ, Alaaji Abubakar Atiku, lo tun wọle ibo abẹle ẹgbẹ…
Category: Ìròyìn
Ibo abẹle PDP:Tambwal juwo silẹ fun Atiku, Nwachukwu fun Wike
Jọkẹ Amọri Gomina ipinlẹ Sokoto, to tun jẹ ọkan ninu awọn oludije sipo aarẹ lẹgbẹ oṣelu…
Wọn tẹ eeyan mọkanlelọgbọn pa lasiko ti wọn fẹẹ lọọ gba ounjẹ ati ẹbun ọfẹ ni Port Harcourt
Ọrẹoluwa Adedeji Eeyan bii mọkanlelọgbọn lawọn ọlọpaa sọ pe o ti pade iku ojiji ni ṣọọṣi…
Oṣere tiata yii pariwo: Ẹ gba mi o, latọjọ ti mo ti ṣojọọbi mi ni itẹkuu lawọn oku ti n yọ mi lẹnu
Monisọla Saka Kayeefi! Inu iboji larakunrin yii ti ṣe ọjọ ibi ẹ. Oṣerekunrin ilẹ Ghana kan…
2023: Ẹgbẹ TOTT rọ Tinubu atawọn oludije yooku lati panu pọ gbe Ọṣinbajo kalẹ
Ọrẹoluwa Adedeji Ẹgbẹ kan, The Ọsinbajo Think Tank (TOTT), ti parọwa si aṣaaju ẹgbẹ oṣelu APC,…
Ọwọ tẹ afurasi mẹta lori ọkunrin agbẹ kan ti wọn pa nibudo iwakusa l’Ọṣun
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti mu eeyan mẹta ti wọn jẹ oṣiṣẹ nibudo…
Ibo abẹlẹ APC Ọyọ: Fọlarin jawe olubori, Adelabu gba ẹgbẹ SDP lọ
Ọlawale Ajao, Ibadan Sẹnetọ Teslim Fọlarin lo jawe olubori ninu idibo abẹle ẹgbẹ oṣelu All Progresives…
Awọn eleyii n gbowo ipa lọwọ awọn onimọto, wọn loṣiṣẹ ijọba Eko lawọn
Faith Adebọla, Eko Ọrẹ timọtimọ ni awọn ọkunrin mẹrin yii, Taiwo Falọdun, ẹni ọdun mejidinlaaadọta, Adedire…
Nitori burẹdi ọgọrun-un Naira, Fulani ṣa Jamiu ladaa pa ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Majisreeti kan to fi ilu Ilọrin ṣe ibujokoo ti paṣẹ pe ki…
INEC fi ọjọ mẹfa kun ọjọ idibo abẹle awọn ẹgbẹ oṣelu ilẹ wa
Ọrẹoluwa Adedeji Ajọ eleto idibo ilẹ wa ti fi ọjọ mẹfa kan kun gbedeke ọjọ ti…
Wọn ti tu Oriyọmi Hamzat silẹ lahaamọ
Iroyin to tẹ ALAROYE lọwọ ni pe awọn ọlọpaa ti tu Oludasilẹ Redio Agidigbo, Oriyọmi Hamzat…