Nitori ọrọ ti ko to nnkan, iyaale ile yii fọbẹ gun ọrẹ rẹ pa

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko niyaale ile kan, Abilekọ Cynthia Aigbondon, to fọbẹ aṣooro  gun ọrẹ rẹ, Oloogbe Basirat Adio, pa lọjọ Aiku, Sannde, ọjọ kọkanla, oṣu Keji, ọdun yii…

Ọwọ tẹ Ayọmide l’Oṣogbo, waya ile onile lo lọọ ji tu

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ayọmide David Popoọla, ẹni ọdun mejilelọgbọn, lọwọ awọn ọlọpaa ti tẹ niluu Oṣogbo…

Mi o mọdi tijọba apapọ ṣe fẹẹ gbe ileeṣẹ banki apapọ ile wa ati   FAAN lọ s’Ekoo – Emir Kano

Adewale Adeoye Emir tilu Kano, Alhaji Aminu Ado Bayero, ti sọ pe bi ebi, iya ati iṣẹ ṣe pọ  laarin…

Adeleke gbe igbimọ kalẹ lati yanju wahala ẹgbẹ oṣiṣẹ kootu ati adajọ agba l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lẹyin nnkan bii oṣu mẹta ti agbarijọ ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ kootu nipinlẹ Ọṣun…

Iwa palapala, inu ṣọọṣi ni tọkọ-taya yii ti n ṣe ‘kinni’ funra wọn tọwọ fi tẹ wọn

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Maiduguri, lawọn ti fọwọ ofin mu awọn tọkọ-taya meji kan, Abilekọ Khadija Adam, to n gbe lagbegbe Ngomari,…

O ma ṣe o, bureeki ọkọ Dyna feeli, lo ba lọọ tẹ ọlọkada pa n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kejila, oṣu Keji yii, ni ọlọkada kan pade iku…

Awọn ara Igbajọ yari fun Adeleke, wọn niluu ko le ṣoro ọba lẹẹmeji

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn ile ọlọmọọba Ọwa Oke-Ode atawọn afọbajẹ niluu Igbajọ, nipinlẹ Ọṣun, ti sọ…

Aara san pa agbabọọlu yii lasiko to n gba bọọlu lọwọ

Adewale Adeoye Ṣe lọrọ ọhun di bo o lọ yago fun mi lasiko ti aara buruku kan san lojiji,…

Nitori bi nnkan ṣe gbowo lori, eyi niye owo-oṣu ti ẹgbẹ oṣiṣẹ fẹ kijọba apapọ maa san

Adewale Adeoye Nitori ojojo to n ṣe ọrọ aje orileede wa, eyi to mu ki gbogbo…

Ijọba gba ọkada rẹpẹtẹ nidii awọn ọlọkada niluu Eko, eyi lohun ti wọn fi i ṣe

Adewale Adeoye Ni bayii,  ijọba ipinlẹ Eko ti lawọn ko ni i fọwọ yọbọkẹ mu ọrọ awọn ọlọkada gbogbo ti wọn joye aleti-lapa,…

Oluwoo n wa Hassan Lawal, o ni ẹbun owo nla wa fẹni to ba ri i

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti kede pe ẹnikẹni to…