Eemọ ree o! Iyaale ile yii pokunso sinu yara ẹ ni Magboro

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ lọwọ lọrọ iyaale ile kan, Oloogbe Idowu Victoria, ẹni ọdun mọkandinlaaadọta to pokunso…

Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko bẹrẹ iwadii nipa agbofinro to gun araalu pa

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti bẹrẹ iwadii nipa iṣẹlẹ bi Insipẹkitọ Taofeek, to jẹ ọlọpaa lagbegbe Ajah, nipinlẹ Eko, ṣe fọbẹ gun araalu kan, Oloogbe…

Eeyan mẹẹẹdọgbọn jona ku lasiko ti mọto akero meji fori sọra wọn

Adewale Adeoye Ero mẹẹẹdọgbọn to wa ninu mọto akero meji kan, Toyota ati Sienna, lo jona deeru lasiko ti mọto…

Ọpẹ o! Awọn ajinigbe ti yọnda pasitọ ijọ Ridiimu ti wọn ji gbe

Ọlawale Ajao, Ibadan O daju pe orin ọpẹ lawọn ẹbi, ololufẹ ati ọpọ ọmọ ijọ Ridiimu…

Ayedatiwa bori ibo abẹle Ondo, eyi lawọn ohun to ṣẹlẹ nibẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Latigba ti ẹgbẹ oṣelu All Progressive Congress lorilẹ-ede yii ti mu ogunjọ oṣu…

Awọn Fulani ji pasitọ Ridiimu atawọn mẹtala mi-in gbe l’Eruwa

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn ajinigbe tun ṣoro nipinlẹ Ọyọ, lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kọkandinlogun (19), oṣu…

O ma ṣe o, ile ya pa awọn ọmọ ileewe meje

Adewale Adeoye Awọn ọmọ ile kewu Almajiri meje ni wọn fa jade labẹ ilẹpa to wo lu wọn mọlẹ lọjọ Abamẹta, Satide, ogunjọ, oṣu Kẹrin, ọdun 2024 yii. Awọn…

Ọwọ ti tẹ Sanni to maa n fọhun bii ẹbọra lati ṣe gbaju-ẹ fawọn araalu

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Adamawa, ni gende kan, Ogbẹni Sani Mamman, ẹni ọdun mọkandinlogoji kan to n ṣe bii ẹbora laarin ilu…

Agbebọn pa ṣọja mẹfa, ọdẹ kan

Adewale Adeoye Pẹlu bawọn oniṣẹ ibi ti wọn n pe ni agbebọn ṣe n lọ kaakiri igberiko, paapaa ju lọ, lawọn…

Loootọ ni mo fipa ba ọmọ araalu mi laṣepọ ni baluwẹ, amọ oun lo fa a o – Godwin

Faith Adebola  Yooba bọ, wọn ni ‘afago kẹyin aparo, ohun oju wa lojuu ri’, owe yii…

Gbese ree o, maaluu bii aadọta jẹ majele, ni wọn ba ku danu n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Tẹkun-tomije lawọn ontaja kan ti wọn n ta maaluu ninu ọja Mandate, Adewọle,…