Ìròyìn

Idi ti Jonathan ko fi le dupo aarẹ lọdun 2023- Falana

Monisọla Saka Idi ti Jonathan ko fi le dupo aarẹ lọdun 2023- Falana Agbẹjọro to tun jẹ ajafẹtọọ ọmọniyan nipinlẹ Eko, Ọgbẹni Fẹmi Falana, ti sọ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, pe aarẹ ilẹ wa tẹlẹ, Goodluck Ebele Jonathan, ko le jade dupo aarẹ to n bọ lọna lọdun 2023, nitori …

Read More »

Lẹyin ti Victor atawọn ọrẹ ẹ fipa ba ọrẹbinrin ẹ lo pọ tan ni wọn ju fọto ẹ sori ẹrọ ayeujara l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Eka to n gbogun ti fifi ipa ba ọmọ kekere lajọṣepọ (Juvenile Welfare Centre), ti ileeṣẹ ọlọpaa Ekiti, ti kede pe ọwọ awọn ti tẹ ọdọ langba mẹrin pẹlu ẹsun pe wọn fipa ba ọmọdebinrin ẹni ọdun mejidinlọgbọn kan lo pọ ni Ado-Ekiti. Gẹgẹ bii Alukoro ileeṣẹ …

Read More »

Arẹgbẹṣọla, Amosun lo mu mi de ọdọ Buhari

Ọrẹoluwa Adedeji Yatọ si ohun ti awọn kan n sọ kiri pe Aṣiwaju Tinubu lo fa Igbakeji Aarẹ, Yẹmi Ọṣinbajo, le Buhari lọwọ fun ipo naa lọdun 2015, ọkunrin naa ti sọ pe ọrọ ko ri bẹẹ o. O ni Gomina ipinlẹ Ọṣun tẹlẹ, Raufu Arẹgbẹṣọla, ati ojugba rẹ to …

Read More »

Lati Sagamu ni Afeez ti lọọ yọ eyin oku to fẹẹ fi ṣoogun owo ni itẹkuu kan n’Ileṣa

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lasiko ti ọmọkunrin ẹni ọdun mẹtalelọgbọn kan, Afeez Odusanya, n yọ eyin oku to fẹẹ fi ṣoogun owo lọwọ ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun tẹ ẹ. Afeez, mẹkaniiki ọkọ akoyọyọ (Truck), ni wọn ka eyin mejila pẹlu eegun-ika ọwọ meji mọ lọwọ. Alakooso Amọtẹkun nipinlẹ Ọṣun, Amitolu Shittu, …

Read More »
//thaudray.com/4/4998019