Lati din ọwọngogo ounjẹ ku, eyi lohun ti Tinubu paṣẹ pe ki wọn ṣe kiakia

Monisọla Saka Pẹlu bi ọwọngogo ounjẹ ati ebi ṣe gba ilu kan, ti awọn araalu si…

Eyi nidi ti mi o fi ba ijọba Eko ṣe fiimu mọ – Iyabọ Ojo

Faith Adebọla Bi ko ba yi ipinnu rẹ pada, awọn ololufẹ fiimu awotunwo ori ẹrọ ayelujara kan ti…

O n rugbo bọ o, gomina Oke-Ọya yii lawọn ko ni i ko ounjẹ lọ sawọn ipinlẹ mi-in mọ

Faith Adebọla Iṣoro aito ati ọwọngogo ounjẹ to gbode kan lorileede yii ti gba ọna mi-in…

Gomina yii figbe bọnu: Ẹ gba mi o, awọn agbebọn fẹẹ wa ji mi gbe

Faith Adebọla Yooba bọ, wọn ni ‘iji to ja to kaṣọ ni yara, kẹni to wọ…

Ọlọpaa ti mu Aisha Jibrin, obinrin to ṣaaju iwọde tawọn araalu ṣe ni Minna

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Niger ti fọwọ ofin mu gbajumọ ajafẹtọọ-omọniyan kan, Abilekọ Alisha Jibrin, to ṣaaju iwọde ita gbangba kan tawọn araalu Minna ṣe lọjọ…

O ma ṣe, nibi ti oloṣelu yii ti n wo bọọlu Super Eagles lọwọ lo ti ṣubu lulẹ, lo ba ku patapata

Adewale Adeoye Ere ati awada lawọn to wa lẹgbẹẹ Oloogbe Cairo Ojuougboh, to ti figba kan wa…

Abiru ki leleyii! Wọn tun ti pa ọba alaye ilẹ Yoruba mi-in o

Adewale Adeoye Ni bayii, ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kogi, ti lawọn maa too fọwọ ofin mu awọn ọdaran kan ti wọn lọọ pa Ọba ilu Elepe Ohi/Ogidi, nijọba…

Wọn ti mu ayederu babalawo meji to n ṣe gbaju-ẹ fawọn araalu

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Edo, ni awọn ayederu babalawo meji kan to n ṣe gbaju-ẹ fawọn araalu agbegbe…

Abiru ki leleyii, awọn agbebọn pa ṣoja mẹta, ọdẹ aduugbo meji, to fẹẹ lọọ gba awọn araalu silẹ

Adewale Adeoye Mẹta lara awọn ọmọ ogun orileede wa kan ti wọn ran lọ pe ki wọn lọọ da alaafia…

O ga o,  olori ọdọ ilu yii pokunso sinu igbo, eyi lohun to fa a

Adewale Adeoye Ni bayii, awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Polaku, nijọba ibilẹ Yenagoa, nipinlẹ Bayelsa, ti sọ pe awọn maa too bẹrẹ iwadii lori bi olori ọdọ agbegbe…

Ile-ẹjọ ti gba beeli awọn akọroyin meji ti ọga Kwara Poli ni wọn ba oun lorukọ jẹ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ keje, oṣu Keji yii, nile-ẹjọ Majisireeti kan niluu Ilọrin, ipinlẹ…