Eyi nidi ti Wasiu Ayinde ko fi ni i ṣayẹyẹ ọjọọbi rẹ lọdun yii

Adewale Adeoye Gbajumọ olorin fuji nni, Wasiu Ayinde Marshal, ẹni tawọn eeyan mọ si ‘K1 De Ultimate’, ti loun ko ni i ṣayẹyẹ ọjọọbi oun lọdun…

Awọn tọọgi da mọto tirela to n ko ounjẹ lona, gbogbo ẹru inu rẹ ni wọn ji ko pata

Adewale Adeoye Ni nnkan bii aago mẹta kọja iṣẹju mẹẹẹdogun, Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu Keji, ọdun 2024 yii, lawọn janduku kan ti…

Ọwọ tẹ ọga ṣọja yii, oun ati tọkọ-tiyawo kan lo n tẹ ayederu owo

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe ‘Zone 2 Command’, niluu Eko, ni ọga ṣọja kan, Ọgagun Ilelabayọ Johnson, ẹni ọdun marundinlogoji atawọn mẹta kan ti wọn fẹsun…

Ọwọ ba Yusuf at’ọrẹ ẹ, awọn akẹkọọ-binrin ni wọn maa n digun ja lole lositẹẹli KWASU 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ni tolohun, owe yii lo ṣe rẹgi…

Awọn eeyan bara jẹ gidigidi nibi isinku Sisi Quadri, eyi lohun ti wọn sọ nipa rẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ka ku lọmọde ko yẹ ni, o san ju ka dagba ka ma…

O ma ṣe o, Sisi Quadri n mura ilu oyinbo lọwọ niku mu un lọ

    Ọrẹoluwa Adedeji Yoo ṣoro ki iku oṣere adẹrin-in-poṣonu nni, Tọlani Qadri Oyebamiji, ti gbogbo…

 Eyi laṣiiri iku to pa Sisi Quadri

Jọkẹ Amọri Bo tilẹ jẹ pe oṣerekunrin ti gbogbo eeyan fẹran daadaa nni, Tọlani Qadri Oyebamiji,…

Ajalu buruku lagbo tiata! Sisi Quadri ku lojiji

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Agbọ-sọgba-nu ni iku ọkan ninu awọn oṣere ilẹ wa tawọn eeyan fẹran daadaa…

Ẹ woju awọn ọdaran ti wọn pa Rianat lasiko to fẹẹ lọọ ra kulikuli l’Ọffa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Aṣe ootọ lowe Yoruba to ni iyan ogun ọdun a maa jo ni…

Gende meji dero kootu l’Akurẹ, foonu ni wọn ji nibi eto isinku Akeredolu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹsọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo ti wọ awọn afurasi ole meji kan, Oluṣẹyẹ Adefila…

Atọlagbe yii buru o! Lẹyin to fipa ba obinrin kan sun tan lo ge ẹran ẹ wẹlẹwẹ, o ba dana sun un ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọtafa-soke yido-bori, b’ọba aye ko ri ọ, tọrun n wo ọ. Ọrọ ikilọ…