Wọn lu baba arugbo pa nitori ọrọ ilẹ, wọn ju oku ẹ seti odo l’Abẹokuta

Gbenga Amos, Abeokuta  Baba arugbo, ẹni ọdun marundinlaaadọrun-un  (85) kan, Jimọh Ọladiran, ti kagbako iku ojiji,…

Ọba fẹ Ọmọọba:Oluwoo ilẹ Iwo ṣegbeyawo pẹlu Ọmọọba Kano

Florence Babaṣọla, Osogbo Oni ọjọ kọkandinlogun, oṣu Kẹta yii, ni ayẹyẹ igbeyawo Oluwoo tilẹIwo, Ọba Abdulrasheed…

Wọn lu Linus pa nibi ija igboro n’Idanre, lawọn ara abule ba sa kuro niluu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gbogbo awọn eeyan abule kan ti wọn n pe ni Ipoba-Ọjọmu, nijọba ibilẹ…

O ṣẹlẹ, awọn ọlọpaa fẹẹ bẹrẹ iyanṣẹlodi lọjọ ipade gbogbogboo ẹgbẹ APC

Adewumi Adegoke Bi awọn ọjẹ wẹwẹ lẹnu iṣẹ ọlọpaa ko ba yi ipinnu wọn lati bẹrẹ…

Sẹnetọ Iyiọla Omiṣore fẹẹ dupo Akọwe apapọ ẹgbẹ APC

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Igbakeji gomina ipinlẹ Ọsun to tun ti figba kan jẹ sẹnetọ, to si…

Buhari ti pada de lati London

Adewumi Adegoke Ọjọ Ẹti, Furaidee, opin ọsẹ yii, ni Aarẹ Muhammadu Buhari pada si ilẹ Naijiria…

Nitori ami-ẹyẹ orileede ti inu rẹ dun ju lọ lagbaaye ti Finland gba, awọn ọmọ Naijiria kan fẹẹ lọ si orileede naa

Afi ki awọn oṣonu, awọn ti inu wọn ki i dun nigba kọọkan, tabi awọn ti…

Ibi ibura awọn oloye ẹgbẹ ni wọn ti n bọ tawọn agbebọn fi ji ọmọ ẹgbẹ oṣelu APC mẹjọ gbe ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ibi ayẹyẹ ibura wọle awọn oloye ẹgbẹ oṣelu Onitẹsiwaju (APC), ni awọn mejọ…

Ara meriiyi ri, wọn ba afọku tọmbila ninu obinrin kan lasiko iṣẹ abẹ  

Iyalẹnu ni ọrọ obinrin ẹni ọdun marundinlogoji kan ṣi n jẹ fun awọn dọkita ọsibitu kan…

Ọwọ tẹ awọn ọlọpaaa to yinbọn mọ ọmọ Poli Eruwa

Ọlawale Ajao, Ibadan Ni nnkan bii aago kan aabọ ọsan ọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ to kọja, niṣẹlẹ ọhun…

Eyi ni idi ti mo fi gba iyawo gomina Anambra tẹlẹ leti-Bianca Ojukwu

Jọkẹ Amọri Bianca Ojukwu, iyawo ọkan ninu awọn agba oṣelu ilẹ Ibo to ti doloogbe bayii,…