Ayedatiwa bori ibo abẹle Ondo, eyi lawọn ohun to ṣẹlẹ nibẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Latigba ti ẹgbẹ oṣelu All Progressive Congress lorilẹ-ede yii ti mu ogunjọ oṣu…

Awọn Fulani ji pasitọ Ridiimu atawọn mẹtala mi-in gbe l’Eruwa

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn ajinigbe tun ṣoro nipinlẹ Ọyọ, lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kọkandinlogun (19), oṣu…

O ma ṣe o, ile ya pa awọn ọmọ ileewe meje

Adewale Adeoye Awọn ọmọ ile kewu Almajiri meje ni wọn fa jade labẹ ilẹpa to wo lu wọn mọlẹ lọjọ Abamẹta, Satide, ogunjọ, oṣu Kẹrin, ọdun 2024 yii. Awọn…

Ọwọ ti tẹ Sanni to maa n fọhun bii ẹbọra lati ṣe gbaju-ẹ fawọn araalu

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Adamawa, ni gende kan, Ogbẹni Sani Mamman, ẹni ọdun mọkandinlogoji kan to n ṣe bii ẹbora laarin ilu…

Agbebọn pa ṣọja mẹfa, ọdẹ kan

Adewale Adeoye Pẹlu bawọn oniṣẹ ibi ti wọn n pe ni agbebọn ṣe n lọ kaakiri igberiko, paapaa ju lọ, lawọn…

Loootọ ni mo fipa ba ọmọ araalu mi laṣepọ ni baluwẹ, amọ oun lo fa a o – Godwin

Faith Adebola  Yooba bọ, wọn ni ‘afago kẹyin aparo, ohun oju wa lojuu ri’, owe yii…

Gbese ree o, maaluu bii aadọta jẹ majele, ni wọn ba ku danu n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Tẹkun-tomije lawọn ontaja kan ti wọn n ta maaluu ninu ọja Mandate, Adewọle,…

Oṣu kẹta ree ti NDLEA ti n wa awọn ogbologboo oniṣowo egboogi oloro tọwọ ba yii

Faith Adebọla  Lẹyin oṣu meji tawọn ẹṣọ NDLEA ti n wa awọn afurasi ọdaran mẹta kan…

Ipo Alaafin: Awọn Ọyọmesi tun pe Gomina Makinde lẹjọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ti ile-ẹjọ ti da ẹjọ ti wọn pe ta ko gomina ipinlẹ…

Baba at’ọmọ ti wọn pa iya onipọnmọ l’Ogijo ti ṣalaye bo ṣe ṣẹlẹ

Monisọla Saka Ṣe ẹ ranti iṣẹlẹ aburu kan tileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun sọ pe o waye…

Wọn ti ri i mu o, dẹrẹba to pa tọkọ-tiyawo sinu ile wọn l’Abuja

Monisọla Saka Amookunṣika ẹda to pa awọn arugbo tọkọ-taya kan niluu Abuja, ninu oṣu Kẹta, ọdun…