Ẹ wo Ibrahim: Igbakeji ọga awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun, ibọn rẹpẹtẹ ni wọn ba lọwọ ẹ

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti fọwọ ofin mu Ọgbẹni Ibrahim AbdulAzeez, ti wọn sọ pe ogbologboo ọmọ ẹgbẹ okunkun ni, ati pe ọpọ igba…

O ma waa ga o, agbebọn mura bii ẹlẹhaa, lo ba pa ọga ọlọpaa meji danu

Adewale Adeoye Ṣe lọrọ ọhun di ẹni ori yọ, ipade dile, lasiko ti agbebọn kan to mura bii ẹlẹhaa lọọ kọju…

Orileede Mali, Niger ati Burkina-Faso ti kuro ninu ajọ ECOWAS

Adewale Adeoye Ni bayii, awọn ijọba ologun ti orileede Mali, Niger ati Burkina-Faso, ti kede pe awọn…

O ma ṣe o, iyawo atawọn ọrẹ ẹ marun-un pẹlu aburo ọkọ ku sinu ijamba mọto lọjọ kan naa

Adewale Adeoye Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu Kin-in-ni, ọdun 2024 yii ni iṣẹlẹ agbọ-kawọ-mọri kan ṣẹlẹ sawọn  idile kan to ṣẹṣẹ ṣegbeyawo alarinrin fawọn ọmọ wọn, ti iyawo…

Iru ifẹ wo ree: Nitori ti ọkunrin ja a kulẹ, akẹkọọ-binrin yii binu gbẹmi ara ẹ

Monisọla Saka Akẹkọọ-binrin onipele keji nileewe gbogboniṣe ijọba apapọ to wa niluu Mubi, nipinlẹ Adamawa (Federal…

Ọpẹ o, wọn ti ri akẹkọọ Fasiti Ilọrin ti wọn ji gbe pada, eyi ni bi wọn ṣe ri i

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akẹkọọ Fasiti ilu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, Moyọṣọrẹ Bright, to wa ni ipele kin-in-ni…

L’Ọṣun, wọn yinbọn pa aṣaaju ẹgbẹ oṣelu PDP to wale lati orileede Amẹrika

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkunrin ọmọ ẹgbẹ PDP kan to jẹ olukọ lorileede Amẹrika, Ọgbẹni Richard Idowu,…

Adajọ ko gba ẹbẹ Udom to gun ọrẹ rẹ pa, wọn ju u sẹwọn Kirikiri

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Oyindamọla Ọgala, tile-ẹjọ giga kan to wa niluu Ikeja, nipinlẹ Eko, ni wọn wọ Ọgbẹni Emmanuel Udom, to gun ọrẹ rẹ pa ba. Ẹsun…

Opin aye de, pasitọ atawọn ọmo ijọ rẹ lọọ digunjale, mọto olowo nla ni wọn ji gbe

Adewale Adeoye Ọdọ awọn agbofinro agbegbe kan lorileede South Africa, ni Pasitọ Lincoln Tichaona, ẹni ọdun mọkandinlogun, atawọn ọmọ ijọ rẹ meji, Ọgbẹni Chigwasa Innocent, ẹni ogoji ọdun, ati Ọgbẹni Johannes Matema, ẹni ọdun mejidinlọgbọn wa bayii. Ẹsun…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, ọrẹkunrin yii pa afẹsọna rẹ danu

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ, ọdọ awọn agbofinro agbegbe Githurai 44, niluu Nairobi, orileede Kenya, ni Ọgbẹni Clinton Mwangi,…

Iyawo mi ti gba nnkan mi-in m’ẹsin, ko ṣetọju emi atawọn ọmọ mọ ninu ile-Bakari

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Doocivir Yawe, tile-ẹjọ kọkọ-kọko kan to wa lagbegbe Nyanya, niluu Abuja, ti i ṣe olu ilu ilẹ wa, lawọn tọkọ-taya…