Tinubu fun awọn ti afẹmiṣofo kọlu nipinlẹ Niger ni aadọta Miliọnu, o tun ṣabẹwo si Babangida

Jọkẹ Amọri Lẹyin to ṣabẹwo si gomina ipinlẹ Niger, Abubakar Sanni Bello, nibi to ti beere…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, Usman pa ọmọọya kan naa mẹta ni Ṣaki

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu kẹta, ọdun 2022 yii nile-ẹjọ sun ẹjọ ọkunrin ẹni ọgbọn…

Ti Buhari ko ba tete buwọ lu abadofin eto idibo ti wọn ṣatunṣe ẹ yii, ẹ fura si i – Ayọ Fayoṣe  

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Ekiti tẹlẹ, Ọgbẹni Peter Ayọdele Fayoṣe, ti ke si Aarẹ orileede wa,…

L’Ọṣun, ori ko eeyan mejila yọ lọwọ iku ojiji

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Eeyan mejila lo bọ lọwọ iku ojiji nibi ijamba ọkọ to ṣẹlẹ loju…

Ẹ maa dajọ iku fun ẹnikẹni to ba ti gbe oogun oloro – Oluwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilẹ Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti sọ pe ọna kan…

Atẹnujẹ ko ba Peter, nitori to n mugbo, adajọ ni ko gba’lẹ kootu fọjọ marun-un

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọdọmọkunrin kan, Peter Igwe, ladajọ kootu Majisreeti kan niluu Ileefẹ sọ pe ko…

Super Eagles gbo ewuro soju awọn agbabọọlu Guinea Bissau pẹlu ami-ayo meji si odo

Jọkẹ Amọri Ẹgbẹ agbabọọlu ilẹ wa, Super Eagles, ti gbo ewuro soju awọn akẹgbẹ wọn lati…

Famuyibọ fẹgbẹ APC silẹ l’Ekiti, o loun fẹẹ dije ninu ẹgbẹ Akọọdu

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Oludije tẹlẹ ninu ẹgbẹ Social Democratic Party, Oloye Reuben Famuyibọ, ti fẹgbẹ Onigbaalẹ…

Mo maa sanwo WAEC awọn ọmọ yin tẹ ẹ ba fibo gbe mi wọle sipo aarẹ Naijiria

Adefunkẹ Adebiyi Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu, baba to ti fi ẹrongba rẹ han lati dupo aarẹ…

Ijamba mọto paayan meji loju ọna Abẹokuta s’Ibadan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Eeyan meji lo doloogbe lọsan-an Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kọkandinlogun, oṣu kin-in-ni, ọdun 2022…

Tọkọ-taya ko tọọgi lọọ lu tiṣa l’Ado-Odo, nitori ọmọ wọn tileewe ni ko gẹrun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Oju bọrọ ko gbọmọ lọwọ ekurọ lọrọ awọn akẹkọọ ileewe girama nipinlẹ Ogun…