Oni POS ni Victor lu ni jibiti tọwọ fi tẹ ẹ n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ ẹṣọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu afurasi kan,…

Alaga APC igun Oyetọla fun Arẹgbẹṣọla lesi, o ni ika, onigberaga ati alaimoore ni 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alaga ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Ọṣun, Ọmọọba Gboyega Famọdun, ti sọ pe ọrọ…

Ẹyin ọmọ Yoruba, ẹ jẹ ka ṣatilẹyin fun Tinubu – MC Oluọmọ

Faith Adebọla, Eko Alaga ẹgbẹ awọn onimọto l’Ekoo, Ọgbẹni Musiliu Akinsanya, tawọn eeyan mọ si MC…

Aṣiṣe nibọn wa to pa ọmọ ọdun meji n’Ilaro- Awọn aṣọbode

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ileeṣẹ aṣọbode ilẹ wa, ẹka ‘Ogun 1 Area Command’, ti ni awọn kabaamọ…

Gomina Seyi Makinde wọle pade pẹlu Ladọja, Lekan Balogun atawọn agba oye Ibadan

Ni Satide, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu kin-in-ni, ọdun yii, ni Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, tilẹkun…

Nitori to ṣe agbere, wọn fun iyaale ile lẹgba ọgọrun-un

Ọbẹ ti baale ile ki i jẹ, iyaale ile ko gbọdọ se e ni ọrọ wọn…

 Eyi ni bi Akala ṣe fa mi goke laarin awọn olorin- Ayefẹlẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan Gbajugbaja olorin Juju nni, Dokita Yinka Ayefẹlẹ, ti ṣalaye bi gomina ipinlẹ Ọyọ…

Mo maa n jẹ ẹya ara eeyan bii nnkan ọmọkunrin, oju, ifun ati gogongo, mo si tun maa n ta a fawọn to ba fẹ-Aminu

Aminu Baba lọkunrin to jokoo yii n jẹ, ẹnu ara ẹ lo fi jẹwọ pe oun…

Nitori ẹbun mọto tawọn ọmọ rẹ fun un lọjọọbi ẹ, Iya Fẹmi Adebayọ bu sẹkun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Inu ẹni ki i dun ka pa a mọra, koda, eeyan a maa…

Lẹyin tawọn Fulani yii sa lọgba ẹwọn Abolongo lọwọ tẹ wọn n’Isẹyin

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun. Aṣeyọri nla ni fawọn ẹṣọ fijilante ilu Isẹyin, lagbegbe Oke-Ogun, nipinlẹ Ọyọ, latari bọwọ wọn ṣe…

Isọkusọ ọrọ ni pe mo ti fọwọ si Tinubu lati dupo aarẹ – Wọle Ṣoyinka

Faith Adebọla, Eko  Onigege ara akọwe-kọwura ilẹ wa nni, Ọjọgbọn Wọle Ṣoyinka, ti sọ pe ọrọkọrọ…